Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Yóbè Pèsè Ajílẹ̀ lọ́pọ̀ Yanturu

0 73

Ìjọba ìpínlẹ̀ Yóbè fi léde ní ọjọ́ Àbámẹ́ta wípé, ó ti ná owó tí ó tó bílíọ̀nù méjì ó lé ọwọ́ mésàn án fún ìpèsè ajílẹ̀ láti ọdún 2019 di àkókò yìí.

 

Dókítà Mairo Amshi, tí ó jẹ́ alámòjútó ètò ọ̀gbìn àti ohun àlùmọ́ọ́nì ni ó fi ọ̀rọ̀ náà léde ní ìlú Dámátúrú.

 

Ó tẹ̀ síwájú pé, ètò náà wà ní ìbámu pẹ̀lú ìpinnu ìjọba àpapọ láti mú ki ouńjẹ pọ̀ yanturu àti láti lé ìsẹ́ wọ ìgbẹ́ ní àwùjọ wa.

Leave A Reply

Your email address will not be published.