Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Nàìjíríà Fi Àwọn Ohun Èlò Fún Ilé Ẹ̀kọ́ Ọ̀gbìn Lélẹ̀

0 150

Mínísítà Ọgbin Àti Ìdàgbàsókè Ìgbèríko, Dọ́kítà Mohammad Abubakar, tì ṣé ìfilọ́lẹ̀ Ibùgbé àwọn Akẹkọọ àti ile ìṣẹ fún Ilé Ẹ̀kọ́ Ọgbin Àti Ìdàgbàsókè Ìgbèríko (ARMTI) ní Olú ìlú Nàìjíríà ní  Abuja. Ezeaja Ikemefuna, Olórí Atotonu (ARMTI) ní ó jẹ kí ó dì mímọ ní Ọjọ́ Abàmẹtá.

 

Abubakar sọ pé èéto yí ni yóò jẹ kì ọ̀nà Ọgbin wà yàrá jù tì àtẹ̀yìnwá lọ, àti wí pé yóò fún ohun Ọgbin wa lágbára síí fún ìlọ́ síwájú Èéto Ọrọ aje wà ní ilẹ̀ Okere àti ọ̀nà tí a lè gbà mu ohùn Ogbin wà gbilẹ nínú idokowo wà.

 

Minisita ní yóò pèsè ìṣẹ yanturu fún àwọn tí wọn mọ̀ nípa ohùn Ọgbin, yóò mú ète Ààbò lórí oúnjẹ, Ẹja sísìn àti ohùn Ọsin wà sì ìmúṣẹ.
Abubakar sọ pe àwọn tí fọwọ́sí ìwé Agbọye tì ó gbilẹ (MOU) pẹ̀lú Washington State University (WSU) lórí ohun Ọgbin tí wọn kò fi ajilẹ gbin àti ọ̀nà tí ó gbilẹ láti kọ Ẹ̀kọ́. O gba àwọn Alamojuto Ilé Ẹ̀kọ́ náà lámọran lati mójú to àwọn ohun èlò náà dára dára ki o bá le tọ́jọ́.

 

Olórí Àgbà Pátápátá fun ARMTI, Dọkítà Olufemi Oladunni sọ pé ni pele, ní pele ni èéto ìdàgbàsókè RTC yóò wáyé.

 

Olubunmi Adeyẹmọ
Leave A Reply

Your email address will not be published.