Take a fresh look at your lifestyle.

Igbákejì Ààrẹ Ní Ọbabìnrin Elizabeth II Gùn Orí Àpèré Fún Ọdún Gbọ́ọ́rọ

Igbákejì Ààrẹ Orílẹ-èdè Nàìjíríà, Ọjọgbọ́n Yẹmi Ọṣinbajo ní Oloogbe Ọbabìnrin Elizabeth II gùn Orí Àpérè fún Ọdún gbọ́ọ́rọ, èyí tí ó mú ọgọrọ Ènìyàn wà péjọ pọ jákèjádò Àgbàye.  Ọ̀rọ̀ yìí wáyé níbí imọyi Olóògbé ni Òrùlé Lancaster ní Ọjọ́…

Àyàjọ́ Ìmọtótó Àgbàye: Ìjọba Ipinlẹ Ọ̀yọ́ Tíì Àwọn Ilé Kán Pá

Ìjọba Ipinlẹ Ọ̀yọ́ ní ìlú Ìbàdàn tíì àwọn ilé ìtajá àti ilé gbígbé kàn pá nítorí ìwà ọbùn àti ìdọ̀tí wọn. Kọmiṣọna fún èéto ààbò àti àlùmọ́ọ́nì ilẹ̀, Ọgbẹ́ní Àbíọdún Òní, ṣàlàyé bí àwọn ilé ìta-ọjà àti ilé gbígbé tí ọ̀rọ̀ yí…

Ilé Ìwòsàn Babcock Ṣé Ìṣẹ Àbẹ Ọkàn Fún ÓÒ Kéré Tán Ẹẹdẹgbẹ̀rún Lè Lọ́kàn Dín Lọ́gọ́ta Ènìyàn

Olórí Fásiti Babcock, Iliṣán Rẹmọ, Ọjọgbọ́n Ademọlà Tayọ, jẹ kí Ó dì mímọ fún wá pé láàrin ọdún mẹ́fà, Ilé Ìwòsàn ìkọní Fásiti wọ́n tí ṣe iṣẹ́ Àbẹ Ọkàn fún Ó kéré tán  ènìyàn mọkàndínlọgọ́tá lé lẹẹdẹgbẹ̀rún.  Méjìdínlógún lè ni Ẹ̀gbẹ́tá ìṣẹ…