Browsing Category
Uncategorized
Ìjọba Nàìjíríà Ń Gbìyànjú Láti Ṣe Ìṣelọ́pọ̀ Súgà Láàrín Ọdún Mẹ́wàá Láti Ìgbà…
Ìjọba Nàìjíríà sọ pé ó ní èròǹgbà láti ṣe àṣeyọrí lórí ìṣelọ́pọ̀ súgà láàrín ọdún mẹ́wàá láti ìgbà yìí.
Mínísítà fún Ìṣòwò àti Ìdókò-òwò, Niyi Adebayo ṣe àfihàn yí ní ìlú Abuja ní…
Olalekan Ishọla Balogun di Olúbàdàn kejìlélógójì
Gomina ipinlẹ Ọyọ, Seyi Makinde ti fi idunnu rẹ han si olubadan tuntun, Ọba Olalekan Ishọla Balogun, Alli Okumade 2, ẹni ti o gba ọ̀pá àsẹ gẹgẹ bi Olubadan kejilelogoji lẹyin ọjọ́ Mejilelaadọrin ti olubadan ana, Oba Saliu Adetunji…
Ètò Òtun Ti Wà Ńi Ìkàlẹ ̀Láti Kojú Ìsòro Ààbò Ní Zamfara
Gómìnà ìpínlẹ̀ Zamfara, Bello Matawale sọ pé ètò tuntun ti wà ní ìkàlẹ̀ láti kojú ìsòro ààbò ní ìpínlẹ̀ Zamfara.
Matawale sọ eyi ni ọjọ Aje, lakoko ti o n ba awọn oniroyin ile-igbimọ sọrọ, lẹyin ti o ṣe ipade ikọkọ…
COVID-19: Orílẹ̀ Èdè Greece bun Nàìjíríà ní milioni kan abẹ́rẹ́ àjẹsára Còrónà
Nàìjíríà ti gba miliọni kan abẹ́rẹ́ àjẹsára COVID-19 Johnson ati Johnson Lati ọwọ Greece.
Mínísítà fún orílẹ̀ èdè Greece lórí ọ̀rọ̀ ọ̀kè ọya, Nikos Dendias sọ pé ẹ̀bùn náà jẹ́ ìgbìyànjú Ààrẹ orílẹ̀ èdè…
Ikọ̀ Agbábọ́ọ̀lù Senegal Da èrùpẹ̀ si gaàrí Ikọ̀ Zimbabwe Nínú Ìdíje AFCON (Sen 1-0…
Lẹyin ti ọpọlọpọ akitiyan ikọ Senegal lati ri ẹyin awọn ikọ Zimbabwe ti fori sọpọn; Sadio Mane, atamatase ikọ agbabọọlu Liverpool ri daju wipe oun fi omije kikoro soju ikọ Zibabwe pẹlu bi o se gba penariti wọle ni isẹju aaya ti ifẹsẹwọnsẹ…
Omi Pọju Ọka Lọ Fun Ikọ Manchester United (Man United 0-1 Wolves)
Nnkan o sẹnu re fun ikọ agbabọọlu Manchester United lọjọ Aje ninu ifẹsẹwọnsẹ pẹlu ikọ Wolves lori papa Old Trafford.
Joao Moutinho, ọmọ orilẹ ede Portugal lo da wọn loro nigba to ku isaju aaya ti ifẹsẹwọnsẹ naa yoo fi pari. Ọkan si odo…
Mínísítà buwọ́lu ilé-iṣẹ́ NITDA láti sèdásílẹ̀ ayélujára
Mínísítà fún ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti Ìṣòwò orí ayélujára, Isa Pantami ti fọwọ́sí ìdásílẹ̀ ilè-iṣẹ́ ìdàgbàsókè ìmọ̀ ẹ̀rọ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ amáyédẹrùn (NITDA) sí ọ́fíísì ìṣẹ̀dá ayélujára …
Ẹ máa fẹ̀sùn ọ̀daràn àti ọlọ̀tẹ̀ kàn wá mọ́- Lai Mohammed
Ìjọba orílẹ̀ èd̀e Nàíjíríà ti sọ pe ọ̀rọ̀ àhesọ àti kòbágùngbé ni ilé -isẹ́ aládàáni tó wà ní orílẹ̀ èdè Amẹrika (United States)ń sọ láti fẹ̀sùn kan orílẹ̀ èd̀e Nàíjíríà lórí ẹ̀sùn pé àwọn ló ń fún…
Kò Sí Ìsinmi Ọlọ́ṣẹ̀ Méjì Fún Àwọn Àguǹbánirọ̀
Wọń ti gba àwọn àguǹbánirọ̀ nímọ̀raǹ láti yàgò fuń àwọn ìriǹ tó lè dá ẹ̀mi wọn légbodò gẹ́gẹ́ bi ìrìn -òde -òru àti ìrìn -àjò láì gba àyè lati ọ̀dọ̀ awọn adarí àjọ naa.
Ninu iroyin kan to jade lati ọdọ…
Nàìjíríà nílò ọ̀kẹ́ àìmọye dọ́là fún ìdàgbàsókè amáyédẹrùn
Ààrẹ Muhammadu Buhari,ti ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà yóò nílò ọ̀kẹ́ àìmọye owó ilẹ̀ òkèèrè tó lé ni tiriọnu dọla fún ètò ìdàgbàsókè ohun amáyédẹruǹ.
Ààrẹ Muhammadu Buhari sọrọ yii lọ́jọ́ Ìsẹ́gun níbi…