Ìjọba Nàìjíríà Ń Gbìyànjú Láti Ṣe Ìṣelọ́pọ̀ Súgà Láàrín Ọdún Mẹ́wàá Láti Ìgbà Yii
Ìjọba Nàìjíríà sọ pé ó ní èròǹgbà láti ṣe àṣeyọrí lórí ìṣelọ́pọ̀ súgà láàrín ọdún mẹ́wàá láti ìgbà yìí.
Mínísítà fún Ìṣòwò àti Ìdókò-òwò, Niyi Adebayo ṣe àfihàn yí ní ìlú Abuja ní ọjọ́ ọjọ́bọ̀ ní ibi ìpàdé mínísítà ọ̀sẹ̀ tí a ṣètò nípasẹ̀ ẹgbẹ́ ti o n bojuto ibaraẹnisọrọ Aare.
O sọ wi pe lọwọlọwọ, orilẹ-ede yii n ṣe agbejade ida marun suga ti o nilo ṣugbọn ijọba n ṣe awọn igbiyanju kikan-kikan lati jẹ ki ọ wa lọpọ fun awọn ọmọ Naijiria.
Tolulope Henry
Leave a Reply