Take a fresh look at your lifestyle.

Ikọ̀ Agbábọ́ọ̀lù Senegal Da èrùpẹ̀ si gaàrí Ikọ̀ Zimbabwe Nínú Ìdíje AFCON (Sen 1-0 Zimb)

0 275

Lẹyin ti ọpọlọpọ akitiyan ikọ Senegal lati ri ẹyin awọn ikọ Zimbabwe ti fori sọpọn; Sadio Mane, atamatase ikọ agbabọọlu Liverpool ri daju wipe  oun fi omije kikoro soju ikọ Zibabwe pẹlu bi o se gba penariti wọle ni isẹju aaya ti ifẹsẹwọnsẹ naa yoo wa si opin.

Ninu isọri yii, bakan naa ni ikọ Guinea di ẹru iya le ikọ Malawi pẹlu ami ayo okan si odo (1-0). Ikọ Guinea lo wa ni tente oke tabili, ti ikọ Senegal si tele. Ikọ Malawi wa ni ipo keta, ikọ Malawi na nipo kẹrin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button