Ààrẹ Muhammadu Buhari,ti ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà yóò nílò ọ̀kẹ́ àìmọye owó ilẹ̀ òkèèrè tó lé ni tiriọnu dọla fún ètò ìdàgbàsókè ohun amáyédẹruǹ.
Ààrẹ Muhammadu Buhari sọrọ yii lọ́jọ́ Ìsẹ́gun níbi ipade apero agbaye COP 26 ní ìlú Glasgow.
Ààrẹ Buhari tún kéde pé ìjọba òun ti se gudu gudu meje , yaya mẹfa lati mu eto idagbasoke ba ohun ameyedẹrun lorilẹ ede Nàìjíríà.
Ààrẹ Buhari tun tẹsiwaju pe awọn eto ti wọn ti gbe kalẹ yóò wulo lọpọlọpọ lati lee mu pupọ ọmọ orilẹ ede Naijiria kuro ninu osi ,ki o to di ọdun 2023
Leave a Reply