Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÁNILÁRAYÁ
This is a category for entertainment news
Rema Yóò Seré Níbi Ayẹyẹ Dreamville Ọdún 2024
Olugba àmì ẹyẹ ati irawọ àkòrín ni, Rema.ti ṣetan lati kọrin pẹlu awọn irawọ Olorin bii Cole, SZA ati Nicki Minaj nibi ọdún ayẹyẹ ti Dreamville to n bọ̀.
Ayẹyẹ náà yóò wáyé ni Dorothea Dix Park ni Raleigh, Àríwá Carolina ni Ojo…
Kizz Daniel Ti Ṣetán láti Gbé Àwo Tuntun Jáde Ni Oṣù Kẹ́ta
Ogbontarigi akọrin, Kizz Daniel ti ṣetan lati gbe orin ti o pé akọle rẹ ni ‘Twe Twe‘.
Lati ọdún 2015 ti o ti gbe orin ti akọle rẹ je ‘Woju‘, ti awọn ololufẹ re si kójẹ wàràwàrà ni o ti di gbajugbaja akọrin takasufe, Afrobeats…
Ààrẹ Tinubu Kẹ́dùn Ìpapòdà Gbajúgbajà Òsèré Méjì
Ààrẹ Tinubu sèdárò pẹ̀lú ìdílé àwọn gbajú-gbajà òsèré méjì tí ó dágbére f’áyé, John Okafor àti Quadri Oyebamiji. Ó sàpèjúwe wọn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó kópa rere láwùjọ látàrí ẹ̀bùn tí olódùmarè fún…
Àdánù Ńlá Ní Ìpapòdà John Okafor Jẹ́- Mínísítà
Mínísítà Fún Àṣà àti Ohun Ìsẹ̀m̀báyé, Hannatu Musawa ti fi àìdùnnú ọkàn hàn látàrí ìkéde ikú gbajúgbajà òsèrè, John Okafor tí gbogbo ayé mọ̀ sí Ọ̀gbẹ́ni Ibu
Adẹ́rìn-ín-pòsónú ẹni ọdún…
Gbájugbajà Òṣèré Tíátà Ògbéni Ibu Ti Jáde láyè.
Gbajugbaja Òṣèré Tíátà ni, ti gbogbo àwọn ènìyàn mọ sí Ọgbẹni Ibu ti saye sílẹ̀.
Òṣèré apanilẹ́ẹ̀rín náà ní o jáde láyè ni ọjọ́ Kejì oṣù kẹta ọdún 2024, ni ilé ìwòsàn Evercare to ni ìlú Eko.
Lati bi ọdún diẹ sẹyìn ni gbajugbaja Òṣèré…
Joy Odiete, Gba Ami Ẹyẹ Toronto Film Festival Excellence Award
Oludasile Blue Pictures Cinema, Joy Odiete, ti gba àmì ẹyẹ tó dara ju ti Toronto International Nollywood Film Festival (TINFF) fún isé to tayo ninu Ipese fiimu ilẹ̀ Adulawọ to see mu yangan .
Joy Odiete jẹ gbajúmọ apin fiimu ka nile tabi…
Boston City Kéde Ọjọ Burna Boy
Ilu Boston ti kéde ọjọ keji oṣù kẹta bíi ọjọ Burna Boy ti awọn alaṣẹ fi ountẹ̀ lu. Ọjọ Abameta, ọjọ keji osu keta to n bọ̀ yìí ni wọn yóò kọkọ se akọkọ irú rẹ.
Ilu Boston ti sọ pe eyi ri bẹẹ láti fi ẹ̀mí im'oore han fún…
Lamido Sanusi, Awolọwọ Yóò Sọ̀rọ̀ Lórí Ipa Àwọn Òsèré Láwùjọ, Ní Ìlú London
Alhaji Sanusi Lamido Sanusi, tí ó jẹ́ Emir ẹlẹ́kẹ̀ẹrìnlá Fún Ìlú Kano ni ìrètí wà pé yóò darí àwọn olùdanílẹ́kọ̀ọ́ lórí ipa àwọn òsèré fún ìdàgbàsókè àwùjọ ní nú ìjíròrò ètò ọrọ̀ ajé tí yóò wáyé…
Wọ́n Yàn Òṣèré-bìnrin Sí Ipò Ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun
Òṣèré-bìnrin, Laide Bakare ni wọ̀n ti yàn sí ipò - Senior Special Assistant (SSA) sí gomina Ademola Adeleke ti ipinlẹ Osun ni ti ẹka ìdánilárayá àṣà àti ìṣe àti ìrìnàjò.
Bakare fi ìdùnnú rẹ̀ hàn lórí òpó ẹ̀rọ…
Ojú Dídùn Ńyọ Tiwa Savage Lẹ́nu
Ni ojú òpó ayélujára instagramu gbajúgbajà akọrin ni, Tiwa Savage ti fi lede pe ojú òun n yọ òun lénu lati nnkan bi odun meji si meta bayii.
" Ẹ̀yin ènìyàn lọ́kùnrin àti lóbìnrin, láti nǹkan bi odun meji si meta ni mo ti ní…