Take a fresh look at your lifestyle.

Boston City Kéde Ọjọ Burna Boy

74

 

Ilu Boston ti kéde ọjọ keji oṣù kẹta bíi ọjọ Burna Boy ti awọn alaṣẹ fi ountẹ̀ lu. Ọjọ Abameta, ọjọ keji osu keta to n bọ̀ yìí ni wọn yóò kọkọ se akọkọ irú rẹ.

Ilu Boston ti sọ pe eyi ri bẹẹ láti fi ẹ̀mí im’oore han fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà to jade wa ni ilẹ Adúláwọ̀ to sí pọju lára àwọn to wa se àtìpó ni ilẹ Amerika ati Massachusetts tí wọn si gbe asa orisirisi wọn larugẹ.

Damini Ebunoluwa Ogulu MFR, ti inangi rẹ n jẹ́ Burna Boy, jẹ́ olukọrin, olootu orin. Olugba àmì ẹyẹ ri náà wa pẹlu awọn bii Wizkid ati Davido gẹgẹ bíi akorin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pẹlu àyájọ́ ọjọ wọn ní ilẹ̀ Amẹrika.

 

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button