Take a fresh look at your lifestyle.

Lamido Sanusi, Awolọwọ Yóò Sọ̀rọ̀ Lórí Ipa Àwọn Òsèré Láwùjọ, Ní Ìlú London

113

Alhaji Sanusi Lamido Sanusi, tí ó jẹ́ Emir ẹlẹ́kẹ̀ẹrìnlá Fún Ìlú Kano ni ìrètí wà pé yóò darí àwọn olùdanílẹ́kọ̀ọ́ lórí ipa àwọn òsèré fún ìdàgbàsókè àwùjọ ní nú ìjíròrò ètò ọrọ̀ ajé tí yóò wáyé ní ìlú London nínú osù karùn-ún

 

Lára àwọn olùdánilẹ́kọ̀ọ́ ni Olóyè Sẹgun Awolọwọ àti Abikẹ Dabiri

 

Edgar, ẹni tí ó se agbátẹrù ètò náà sàlàyé pé, ètò náà yóò wáyé ní ilé ìgbafẹ́ Pullman, ilu London èyí tí yóò ní àfojúsùn ipa àwọn òsèré nínú ìdàgbàsókè ètò ọrọ aje lawujọ.

 

 

Comments are closed.

button