Browsing Category
ÌRÒYÌN ÀṢÀ ÀTI ÌṢE YORÙBÁ
This is a category for culture and life news
Erín wó! Ẹja Nla Lọ! Olúbàdàn pakòdà
Gomina ipinle Oyo, Seyi Makinde fi Olubadan ti Ile Ibadan, Oba Saliu Adetunji, Aje Ogungunniso1 ti o pa ipo da ni eni odun metalelaadorun (93) we apejuwe asiwaju rere.
Makinde, eni ti o fi aidunnu re han si ipapoda oba alaye ohun fi…
Ẹ máa fojú yẹpẹre wo àsà Yorùbá, ẹ gbé èdè, àṣà, lítíréṣọ́ Yorùbá…
Ọọniriṣa Alayeluwa, Ọba Adeyẹye Ogunwusi Ọjaja Keji, Ọọni Ifẹ ti pe fun gbigbe aṣa ati ede Yoruba larugẹ nipa lilo oriṣiiriṣi ọna .
Ọọniriṣa, ẹni ti ỌbaAdebisi Layade (JP), Alara Oodaye ti Ilu Ara ni Ile-Ifẹ ni Ipinlẹ…
Gbogbo pápá ìseré ẹlẹ́kùnjẹkùn tó wà jákè- jádò ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ni yóò gba àtúnse…
Gomina ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́,Seyi Makinde ti ní gbogbo pápá ìseré ẹlẹ́kùnjẹkùn tó wà jákè- jádò ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ni yóò gba àtúnse to mọnyan lórí.
Seyi Makinde sọrọ yii lasiko ti wọn n síde papa isere Lekan Salami to wa ni…
Aarẹ Buhari kí Ẹbí Itsekiri kú orí-ire
Aarẹ Muhammadu Buhari ti kí gbogbo àwọn ẹbí Itsekiri nílé àti lókè òkun, bí wọ́n se ti fi Ọmọ Ọba Tsola Emiko se Olú Warri ti ọ̀kanlelogún(21st) ní Ọjọ́ Abámẹ́ta Osù Kejọ, Odún 2021.
Aarẹ ki awọn ara ilu naa fun bibori…
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní dandan jẹ́mánì gbọ́dọ̀ dá gbogbo àwọn nkàn ìṣẹ̀ǹbáyé tí…
Ìjọba Nàìjíríà ti bèèrè fún ìdápadà gbogbo àwọn ojì-din-lẹwá le ni ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́fà Idẹ ti ilu Benin tí wọ́n gbẹ́sẹ̀ lé ní orílẹ̀-èdè Áfíríkà ní ọdún 19th, tí wọ́n sì sọ ibùgbé rẹ̀ di ilé-ìṣọ́ Jẹ́mánì.…
Ètò Oúnjẹ lọ́pọ̀ yanturu yóò gbọn òṣì dànù-igbákejì Òsíǹbàjò
Igbákejì ààrẹ, orilẹ ede Naijria, Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀síńbàjò sọ pé,ìgbìyànjú orílè-èdè láti pèsè oúnjẹ lọ́pọ̀ yanturu jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára ilànà láti dẹ́rù bòṣì jákèjádò orilẹ ede Nàìjíríà.
Ọjọgbọn…
Ẹ máa jẹ́ kí Àsà àti Ìse Yorùbá wọlẹ̀ :ADACI
Ètò ìgbédìde àsà Ilẹ̀ Yorùbá tó wáyé ni gbọ̀ngan Cultural Center Kuto, Abẹokuta ní ìpínlẹ̀ Ogun, abala kan nínú àjọ agbásàga kan lókè òkun ìyẹn African Diaspora Ancestral Commemoration Institute tó wà ní ìlú…