Take a fresh look at your lifestyle.

Ètò Oúnjẹ lọ́pọ̀ yanturu yóò gbọn òṣì dànù-igbákejì Òsíǹbàjò

0 552

Igbákejì ààrẹ, orilẹ ede Naijria, Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀síńbàjò sọ pé,ìgbìyànjú orílè-èdè láti pèsè oúnjẹ lọ́pọ̀ yanturu jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára ilànà láti dẹ́rù bòṣì jákèjádò  orilẹ ede Nàìjíríà.

Ọjọgbọn Ọsinbajo lọjọ iṣẹgun sọ eyi di mimọ nibi ti wọn ti ṣi Ifọrọwerọ Apapọ Iṣọkan ti Orilẹ-ede lori Apejọ Awọn Eto Ounjẹ ti Ajọ Agbaye 2021 se niluu  Abuja

Ijiroro naa da lori ọna lati ipese  ounjẹ lọpọ janturu ati lati ṣaṣeyọri awọn ẹro Idagbasoke alagberọ kẹtadin-logun,

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button