Take a fresh look at your lifestyle.

Aarẹ Buhari kí Ẹbí Itsekiri kú orí-ire

Ademọla Adepọju

0 156

Aarẹ Muhammadu Buhari ti kí gbogbo àwọn ẹbí Itsekiri nílé àti lókè òkun, bí wọ́n se ti fi Ọmọ Ọba Tsola Emiko se Olú Warri ti ọ̀kanlelogún(21st) ní Ọjọ́ Abámẹ́ta Osù Kejọ, Odún 2021.

Aarẹ ki awọn ara ilu naa fun bibori awọn wahala ti o sẹlẹ leyin lati igbati wọn  ti yan Olu-Warri ti  akọkọ, O si tun rọ awọn ti inú ba n bi  lati yanju wahala naa ni itubi-inubi  ki alaafia ati ifọkanbalẹ ba le wa ni ipinlẹ naa.

 

 

 

 

 

 

 

Hamzat Damọla

Leave A Reply

Your email address will not be published.