Take a fresh look at your lifestyle.

Erín wó! Ẹja Nla Lọ! Olúbàdàn pakòdà

Abiọla Ọlọwẹ latiIbadan

0 424

Gomina ipinle Oyo, Seyi Makinde fi Olubadan ti Ile Ibadan, Oba Saliu Adetunji, Aje Ogungunniso1 ti o pa ipo da ni eni odun metalelaadorun (93) we apejuwe asiwaju rere.

Makinde, eni ti o fi aidunnu re han si ipapoda oba alaye ohun fi ikinni e ku ara-fera ku ranse si idile Olubadan to waja, gbogbo igbimo Olubadan ati gbogbo omo bibi ilu Ibadan patapata

Nigba ti akowe iroyin fun gomina, Taiwo Adisa n gba enu gomina soro, o je ki o di mimo pe Oba Saliu Adetunji Aje Ogungunniso1 sa gbogbo ipa re fun idagbasoke ati ilosiwaju Ilẹ̀ Ibadan gege bi asiwaju ni Ile Afrika.

Gomina Seyi Makinde wa gba adurape  ki Olorun da aabo rẹ bo gbogbo oba, ko si fun won ni ẹmi gigun ati alaafia lati le dari awọn eniyan won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button