Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

Ó GBÓNÁ FẸLI-FẸLI

This is a category for LATEST NEWS

Gómìnà Tambuwal dín ìséde oní Wákàtí mẹ́rìnlé-lógún kù Ní Ìpínlẹ̀ Sókótó

Ní Àtẹ̀lé ìfitónilétí kan nípasẹ̀ Àwọn olórí Ààbò ní Ìpínlẹ̀ Sókóto,́ Gómìnà Àmínù Wàzírì Tambuwal, ti pàṣẹ láti dín ìséde oní wákàtí -lógún ọ̀hún kù ní  Ìpínlẹ̀ náà. Ilana isede ti wọn tun…

Àwọn iṣẹ́ àkànṣe:Ẹ dá ṣẹ̀ríà fún àwọn olùgbaṣẹ́ṣe tí kò dúró déédé

Ìgbìmọ̀ tó ń mójútó owó ìfúnni ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga (TETFund) ní Nàìjíríà, sọ pé ó ti fún àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga  tí ó ń jàǹfàní láti inú àwọn ìṣedúró rẹ̀ láṣẹ láti fòpin sí iṣẹ́ náà àti àwọn…

Ọ̀ṣun 2022: Ọ̀gọ̀ọ́rọ́ Àwọn Olólùfẹ́ PDP ń Yípadà sí APC Ní ìjọba ìbílẹ̀ Ayédáadé

Ipò ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò pàtàkì nípínlẹ̀ Ọ̀sun, People’s Democratic Party, PDP, ti dín kù gan-an nígbà tí ó lé ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta lára ​​àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀ ló ti kéde pé àwọn fẹ́ dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressive Congress, APC, ní…

NGO ṣe ìfilọ́lẹ̀ Ilé-akéde fún oko dídá ní Nàìjíríà

Láti ṣe àlékún ìṣelọ́pọ̀ àgbẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ẹgbẹ́ tí kìí ṣe tìjọba (NGO), ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ ilé-akéde asọ̀rọ̀mágbèsì fún iṣẹ́ ọ̀gbìn  láti dé ọ̀dọ̀ àwọn àgbẹ̀ ní àwọn agbègbè ìgbèríko lórí…