Browsing Category
Ó GBÓNÁ FẸLI-FẸLI
This is a category for LATEST NEWS
Ààrẹ Tinubu gúnlẹ̀ sí ìlu Èkó lẹ́yìn àbẹ̀wò ìkẹ́dùn sí Plateau
Ààrẹ Bọla Tinubu ti gúnlẹ̀ sí ìlú Èkó fún ìsinmi Guudu Fúráìde (Good Friday), lẹ́yìn tí ó kúrò ní Jos, ìpínlẹ̀ Plateau, níbi tí ó ti lọ ṣèkẹ́dùn pẹ̀lú àwọn afaragbà àti ẹbí tí àjálù burúkú tó ṣẹlẹ̀…
Adarí Nàìjíríà gúnlẹ̀ sí Jos
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti gúnlẹ̀ si Jos, olú ìlú Plateau, Àrewá Àringbùngbùn Nàìjíríà, láti kẹ́dùn pẹ́lu ìjọba àti àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ náà lórí ìkọlù ìyìnbọn tó ṣẹlẹ̀ láìpẹ́ léèyí tí ó mú ẹ̀mí…
Ààrẹ Tinubu ti pàṣẹ kí wọ́n ṣàwárí, kí wọn ó sì lo ẹ̀rọ ayàwòrán AI ẹgbẹ̀rún márùn…
Ààrẹ Bola Tinubu ti pàṣẹ fún ológun Nàìjíríà àti Agbófinró Nàìjíríà láti ṣàwárí àwọn tó wà nídìí ìkọlù tó burújàì tó wáyé ní Angwan Rukuba ní Jos, Ìpínlẹ̀ Plateau.
O tun paṣẹ lilo ẹgbẹrun ẹrọ…
Àwọn Ọmọ Ilé-igbimọ Aṣofin Kano mẹjọ ti pada Sínú Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC Láti Inú Ẹgbẹ́ Òṣèlú NNPP
Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano, Abba Yusuf, ti rí ìyípadà ńláǹlà nínú oṣèlú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ní Abuja nígbà tí àwọn mẹ́jọ nínú ilé ìgbìmọ̀ aṣojú sòfin láti ìpínlẹ̀ Kano ti fi ẹgbẹ́ òṣèlú New Nigeria Peoples Party (NNPP) padà sínu ẹgbẹ…
Ilé-igbimọ Aṣòfin Nàìjíríà Ti Gba Ètò Ìṣúná Tó Dín Díẹ̀ Ní Àádọ́rin Tíríníọ̀nù Náírà, N68.3Trn Ti…
Ilé-igbimọ aṣofin Naijiria ti gba Isuna ọdun 2026 wọlé lẹhin ti o ti fi owo tó lè diẹ ni Tirilonù,N9.3 mẹsan Naira kun, bi Aare Bola Tinubu ti béèrè fún bí àfikún, ti o mu iye naa wa si owó to din diẹ ni Àádọ́rin Tirinionu Náírà, N68.3Trn.…
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Fọwọ́ Sí Ẹ̀bùn Fífúnni Fún Ètò Ìwádìí
Ìjọba Àpapọ̀ ti fọwọ́ sí ìdásílẹ̀ Ètò ẹ̀bùn olodọodún, "Nigeria National Laureate Annual Prize Programme", ètò pàtàkì kan tí a ṣe láti dá àwọn ìwádìí ẹ̀kọ́ tó tayọ, ìtayọ ọpọlọ, àti àwọn ìṣẹ̀dá tuntun tó ṣeé ṣe ní ti ìṣòwò mọ̀ láti ọ̀dọ̀…
Àjọ NGF Kẹ́dùn Pẹ̀lú Ìjọba Ìpínlẹ̀ Plateau Lórí Ìkọ̀lù Agwan Rukuba
Àjọ The Nigeria Governors’ Forum (NGF) ti kẹ́dùn pẹ̀lú àwọn ara Agwan Rukubati ipinlẹ Plateau nibi ti ọ̀gọ̀ èrò ti gbẹmi mi ti wọ́n sì sọ ọpọ eniyan di aláabọ̀ ara.
Èyí jẹyọ nínú gbólóhùn ààrẹ àjọ àwọn Gómìnà, AbdulRahman…
Ààrẹ Tinubu Ní Ọmọ Ọdún Mẹ́rìnléláàádọ́rin: Ètò Àtúnṣe Nàìjíríà Gba agbára
Agbẹjọ́rò Àgbà àti Mínísítà fún eto Ìdájọ́ Nàìjíríà, Lateef Fagbemi, ti pe Ààrẹ Bola Tinubu ní “alátúnṣe tí kò wọ́pọ̀,” ó sì fi hàn pé òun ni olórí àwọn tó ń darí orílẹ̀-èdè tó pọ̀ jùlọ ní Áfíríkà sí àtúnṣe ọrọ̀ ajé àti…
Àjọ NGF Ki Ààrẹ Tinubu Bi O Ti Pé Ọdún Mẹ́rìnléláàádọ́rin, Wọn Gbósùbà Fún Ìdari Rẹ̀
Ìgbìmọ̀ Àwọn Gómìnà Nàìjíríà, NGF ti dọ̀wọ́ ìdùnnú sí Ààrẹ Bola Tinubu ní ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọdún Mẹ́rìnléláàádọ́rin rẹ, Wọn yin fún ìdarí rẹ̀ àti ìwà Akin rẹ sí ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè yìí.
Nínú ìkéde kan tí Alága Àpérò àti Gómìnà…
Àwọn Adarí Kí Àtúnṣe Ààrẹ Tinubu Bí Ó Se Di Ẹni Ọdún Mẹ́rìnléláàdọ̀rin
Igbákejì Ààrẹ Nàìjíríà, Kashim Shettima, Ààrẹ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Godswill Akpabio, Abẹnugan Ilé Ìgbìmọ̀ Asojú Sòfin, Tajudeen Abbas, àti àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ ti gbóríyìn fún ètò àtúnṣe Ààrẹ Bola Tinubu, bí ó ṣe ń ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí…