Browsing Category
ÌRÒYÌN ÀṢÀ ÀTI ÌṢE YORÙBÁ
This is a category for culture and life news
Asiwaju Bola Ahmed Tinubu fi Aláàfin Ọ̀yọ́ tó wàjà, Ọba Lamidi Adeyemi III wé “ọpọ́n…
Asiwaju Bola Tinubu ló sọ ọ̀rọ̀ yí di mímọ̀ ní àsìkò tí wọ́n ṣe ádùrá ọjọ́ kẹjọ ní ìrántí ìpapòdà Aláàfin Ọ̀yọ́, Ọba Lamidi Adeyemi III. Ètò ọ̀hún ló wáyé ní Aganju tó wà ní Ààfin ìlú Ọ̀yọ́, ní ìpínlè Ọ̀yọ́ tó wà ní ẹkùn gúsù Iwọ̀ oòrùn…
Gómìná Ṣèyí Mákindé Kẹ́dùn Ikú Aláàfin Ọ̀yọ́, Ọba Làmídì Adéyẹmí III
Gómìná Mákindé, ẹni tí ó fi ìkíni ẹkú ará fẹ́rakù ránṣé sí ìgbìmọ̀ Ọ̀yọ́mèsì, ìdílée Ọba Làmídì Adéyẹmí III, àwọn ọmọ bíbí ìlú Ọ̀yọ́ àti gbogbo ọmọ Ilẹ̀ káàrọ́-ọ̀ jíire nígbàtí ó gbà ládùráà kí…
Àdánù ńlá ló sẹ lẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́: Ọmọọba Akeem Adeyẹmi
Ọmọọba Akeem Adéyẹmí tó s'ojú ẹkùn Ọ̀yọ́ ní Ilé ìgbìmọ̀ asòfin orílẹ̀ èdè Nàìjírìa ló so òrò yí di mímọ̀ ní Ààfin ní ìlú Ọ̀yọ́, ní ẹkùn gúsù Ìwọ òòrùn orílẹ̀ èdè Nàìjírìa nígbàtí ó sàlàyé…
IGI ǸLÁ WO, ALÁÀFIN Ọ̀YỌ́,ỌBA LAMIDI ADEYẸMI PAPÒDÀ
Iroyin to n tẹ wa lọwọ ni yajoyajo sọ pe Alaafin ti ilu Oyo, Oba Lamidi Adeyemi ti jáde láyé.
Ẹni ọdun mẹtalelọgrin ni Alaafin nigba to jade laye, oun si ni Alaafin to ti jọba fun odidi ọdún mejilelaadọta.
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́…
Ẹ jáwọ́ nínú dídábẹ́ fún àwọn ọmọbìnrin-Oluwakemi Olawoyin
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ pẹ̀lú àjọsepọ̀ ajọ Hacey Health Initiative ló se àgbékalẹ̀ ìdánilẹ̀ẹ̀kọ́ fún awọn akọroyin ni ipinlẹ Ọ̀yọ́ lori ipa ti wọn le ko lati fi opin si ìdábẹ́ fun awọn ọmọbinrin (Female Genital Mutilation, FGM)…
Emir Kaiama fi Ahmad Lawan, AbdulRahman AbdulRazaq jẹ oyè Magayaki ,Kaura Kaiama
Adari ile igbimọ asofin agba, Ahmad Lawan ati gomina ipinlẹ Kwara ,AbdulRahman AbdulRazaq ni Emir ti illu Kaiama ti fi jẹ oye Magayaki ati Kaura Kaiama lọjọ Aiku yii..
Emir ti ilu Kaiama ,Alhaji Muazu Shehu Omar ni isẹ ribi-ribi ti…
Olalekan Ishọla Balogun di Olúbàdàn kejìlélógójì
Gomina ipinlẹ Ọyọ, Seyi Makinde ti fi idunnu rẹ han si olubadan tuntun, Ọba Olalekan Ishọla Balogun, Alli Okumade 2, ẹni ti o gba ọ̀pá àsẹ gẹgẹ bi Olubadan kejilelogoji lẹyin ọjọ́ Mejilelaadọrin ti olubadan ana, Oba Saliu Adetunji…
Mi ò ní yí padà kúrò lórí ìlànà bí wọ́n ṣe ń jẹ olúbàdàn -Ṣèyí Mákindé
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ṣèyí Mákindé ṣe àbẹ̀wò ẹkú araá-fẹ́ra kù sí opó Ọba Sálíù Adétúnjí, Ajéogungun I, Olúbádàn ti ìlú Ìbàdàn tí ó sì fi àsìkò ọ̀hún sèlérí pé ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ yóò ṣe ayẹyẹ…
Olúbàdàn: Àdúrà Ọjọ́ Kẹta wáyé lẹ́yìn ìpapòdà ọba aládé
Lọ́jọ́ Iṣẹ́gun,ogunlọ́gọ̀ àwọn ọmọ Ìbàdàn àti àwọn ará ílú péjọ sí Ààfin Pópóyemoja ti Olóògbé Ọba Sálíù Adétúnjí, fún àdúrà ọjọ́ kẹta ọba Olúbàdàn tó wàjà.
Adura naa bẹrẹ ni nnkan bi aago mẹsan…
Erín wó! Ẹja Nla Lọ! Olúbàdàn pakòdà
Gomina ipinle Oyo, Seyi Makinde fi Olubadan ti Ile Ibadan, Oba Saliu Adetunji, Aje Ogungunniso1 ti o pa ipo da ni eni odun metalelaadorun (93) we apejuwe asiwaju rere.
Makinde, eni ti o fi aidunnu re han si ipapoda oba alaye ohun fi…