Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ
This is a category for business news
Ààrẹ Buhari gbé è̀to okòòwò Nàíjíríà lọ sí Saudi Arabia
Aarẹ orilẹ ede Naijria, Muhammadu Buhari ti tun gbe anfaani eto idokoowo lọ fun awọn to n gbe ni orilẹ ede Saudi Aarbia lati wa da okoowo silẹ lorilẹ ede Naijria.
Ogbontarigi nipa eto epo rọbi ,afẹfẹ gaasi , eto ọgbin , ìwakùsà ni …
E-Naira: Ààrẹ Buhari sèfilọ́lẹ̀ owó orí ẹ̀rọ ayélujára
Ààrẹ orìlẹ̀ èdè Nàíjíríà Muhammadu Buhari ti ṣe ifilọlẹ E-Naira, owo ẹrọ ayelujara.
Ayẹyẹ naa waye lọjọ Aje ni ile aarẹ to wa niluu Abuja.
Aarẹ sọrọ yii lasiko ti alakoso ile-ifowopamọ ti orilẹ ede Naijiria,(Central Bank of…
Ẹ dẹ́kun nípa bíba àwọn ọ̀pá epo jẹ́ – à̀arẹ Buhari
Aarẹ orilẹ ede Naijiria,Muhammadu Buhari ti rọ awọn oludari Ogoni to wa ni ẹkùn Niger-Delta lati tubọ maa rọ awọn eniyan lati maa daabobo awọn ohun ìnì bii ọ̀pá epo rọbi ati awọn ti wọn lo lati pọn epo rọbi ni orilẹ ede yii.…
ẹ se isẹ́ yín bí isẹ́, ẹ̀yin ilé-isẹ́ a-dójú-tòfò
Aarẹ orilẹ ede Naijiria, Muhammadu Buhari ti rọ awọn ile-isẹ a-doju-tofo lati maa se isẹ wọn bi isẹ́ lorilẹ ede Naijiria , ni eyi ti wọn yoo se lee máa mu ileri wọn sẹ fun awọn onibara wọn.
Aarẹ sọrọ yii lọjọBọ lasiko ti ẹgbẹ akojọpọ…
Ààrẹ Buhari gbóríyìn fún àjọ UNDP
Aarẹ Muhammadu Buhari ti gboriyin fun isẹ takun-takun ti ẹ̀ka ajọ agbaye to n mojuto eto idagbasoke n se lorilẹ ede Naijiria papaap julọ lati pese awujọ to se e gbe fun awon to wa ni ẹkun ila oorun Ariwa orilẹ ede Naijiria.
Aarẹ sọrọ…
Máa bá isẹ́ rẹ lọ,ààrẹ Buhari tún yan Milland Dikio padà fún ìgbàkejì
Aarẹ orilẹ ede Naijiria , Muhammadu Buhari tun ti fọwọsi ọdun kan fun igba keji miran fun yiyan alakoso fidiẹ fun eto iranwọ ijọba apapọ fun awọn to gba aforiji .
Wọn yan Dikio gẹgẹ bi alakoso fidiẹ ni osu kẹjo , ọdún 2020,.Lasiko…
A o parí àwọn isẹ akanse ko to di ọdun 2023- Aarẹ Buhari
Aarẹ Muhammadu Buhari ti fi ara-ilu Naijiria lọkan balẹ pẹ isẹ akansẹ ori afara keji to wa ni Niger, ipinlẹ Eko si ilu Ibadan ti ijọba apapọ dawọ le ni wọn yoo pari ki ijọba yii to pari saa keji ti wọn gùnlé.
Aarẹ sọrọ yii lọjọ Aje…
Osinbajo yóò máa sojú ààrẹ Buhari ní London níbi ìpàdé UN
igbakeji aarẹ orilẹ ede Naijiria, ọjọgbon Yemi Osinbajo ni yoo maa fi ilu Abuja silẹ lọ si London lati lọ soju aarẹ Muhammadu Buhari nibi ipade ijiroro ajọ agbaye lori iyipada ohun amusagbara lorile ede Afirika, paapaa julọ ni orilẹ ede…
Igbákejì ààrẹ,Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀sínbàjò polongo ìtẹ̀sìwájú lórí Ìṣòwò iṣẹ́ àkànṣe…
Igbákejì ààrẹ orílẹ̀ -èdè Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò sọ pé àwọn akitiyan ti ó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ́ láti fi òpin sí ìdàgbàsókè àwọn iṣẹ́ àkànṣe gáásì ní ilẹ̀ adúláwọ̀ lòdì sí àwọn ìpilẹ̀…
Ẹgbẹ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Nàíjíríà (NANS) sèlérí láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àjọ EFCC láti…
Àgbárijọ ẹgbẹ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà (NANS) ti seleri láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹlu àjọ tó ń gbógun ti ìwà ìbàjẹ́ àti síse owó ìlú kúmọkùmọ, EFCC láti dojú ìjà kọ ìwà jàǹdùkú orí ẹ̀rọ…