Aarẹ orilẹ ede Naijiria , Muhammadu Buhari tun ti fọwọsi ọdun kan fun igba keji miran fun yiyan alakoso fidiẹ fun eto iranwọ ijọba apapọ fun awọn to gba aforiji .
Wọn yan Dikio gẹgẹ bi alakoso fidiẹ ni osu kẹjo , ọdún 2020,.Lasiko ti alako de ipo rẹ ni o ti yanju awọn isoro to n dojukọ ajọ Niger Delta.
Oloogbe aarẹ Umaru YarÁdua lo da ajọ 2009, eto iranwọ ijọba apapọ fun awọn to gba aforiji silẹ lati maa setọju awọn ajijagbara ti ẹkun Niger-Delta lasiko ti wọn fi iwa ipá wọn silẹ.
Leave a Reply