Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ
This is a category for business news
Mínísítà Gbé Oríyìn Fún Dídá Ilé Isẹ́ Sílẹ̀ Ní Ìlú Calabar
Wọ́n ti se àpèjúwe dídá ilé isẹ́ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà kan gbógì láti gba àwọn ènìyàn sísẹ́, wíwá ọ̀nà àtijẹ àti lílé ìsẹ́ wọ ìgbẹ́ fún àwọn ènìyàn ìlú Calabar, ìpínlẹ̀ Cross River.
…
Ààbò Tó Gbopan Yóò Wà Lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà Láìpẹ́ – Àárẹ̀ Buhari
Ààrẹ Muhammadu Buhari ní pẹ̀lú àwọn irú ẹrọ títún àti igbaradi àwọn ọmọ Ogún Nàìjíríà, àìsí ààbò ní Nàìjíríà yóò di òún àtijọ́ láìpẹ́.
Ààrẹ Buhari n sọrọ ní ìlú New York lásìkò ìpàdé ránpẹ́ pẹlú Alákóso Àgbà orílẹ-èdè Ireland,…
Ilé Isẹ́ Ìfìwé Ráńsẹ́ Ní Adarí Titun
Mínísítà fún ètò ìbá araẹni Sọ̀rọ̀ , ọ̀jọ̀gbọ́n Isa pantami ti bu ọwọ́ lu ìyànsípò ọ̀gbéni Bulus Yakubu gẹ́gẹ́ bíi adelé titun ilé isẹ́ ìfìwé ráńsẹ́ àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà, lẹ́yìn tí wọ́n ti já ewé gbélé rẹ…
Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìpínlẹ̀ kogí Dá Dangote Ní Ọwọ́ Kọ́ Ní Ìbílẹ̀ Méjì
Ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Kogi ti pa àse fún ọ̀gá ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ náà láti dá ilé isẹ́ Dangote dúró ní ìjọba ìbílẹ̀ olamaboro àti Ankpa ní ìpínlẹ̀ Kogi.
Eléyìi ́kò sẹ̀yìn ìpalára tí ilé isẹ́…
Ìbásepọ̀ Ọrọ̀ Ajé Tí Ó Múná Dóko Se Pàtàkì Pẹ̀lú Orílẹ̀ Èdè Amẹ́ríkà
Ààrẹ Muhammadu Buhari ti se àpèjúwe ìbásepọ̀ ọrọ̀ ajé tí ó wà láàrin orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà pẹ̀lú Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí èyí tí ó gbajúmọ̀, tí ó sì dán mánrán. Ó sì se pàtàkì láti ríi pé ìbásepọ̀ náà…
Orílẹ-èdè Nàìjíríà Gbero Làti Pa Ìyè Owo Ti O To Ẹdẹgbẹta Bílíọ̀nù Náírà (N500b) Ni Ọdun 2023
Ìgbìmọ̀ Ibaraẹnisọrọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, NCC ti ṣe àfihàn ètò rẹ̀ láti ṣé ipilẹṣẹ tó jù ẹdẹgbẹta biliọnu náírà (N500b) ní ọdún 2023 nípasẹ 5G spectrum.
Igbákejì Alága Alase tí NCC, Ọjọgbọn Umar Danbatta, fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ ni Abùjá,…
Síse Àmójútó Ìpèsè Ohun Èlò Ní Abẹ́lé Se Pàtàkì
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Anambra, Ọ̀jọ̀gbọ́n Charles Soludo ti pè fún fífi ọwọ́ bàbàrà mú àwọn ohun èlò tí a pèsè ní abẹ́lé, nítorí pé ó jẹ́ ọ̀nà ìpèsè isẹ́ tí ó sì máa ń mú búrùjí bá ọrọ̀ ajẹ.
…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Yóbè Pèsè Ajílẹ̀ lọ́pọ̀ Yanturu
Ìjọba ìpínlẹ̀ Yóbè fi léde ní ọjọ́ Àbámẹ́ta wípé, ó ti ná owó tí ó tó bílíọ̀nù méjì ó lé ọwọ́ mésàn án fún ìpèsè ajílẹ̀ láti ọdún 2019 di àkókò yìí.
Dókítà Mairo Amshi, tí ó jẹ́…
Ìbásepọ̀ Ọrọ̀ Ajé Wáyé Láàrin Orílẹ̀ Èdè Russia Ati India
Orílẹ̀ èdè Rusia àti India ti parí gbogbo ètò láti se àfikún àti ìgbélárugẹ fún ìbásepọ̀ lórí ètò ọrọ̀ ajé, ohun àmúsagbára láàrin ara wọn
Eléyìí jẹyọ lẹ́yìn ìpàdé tí ó wáyé láàrin àrẹ orílẹ̀…
Àwọn Ìlé-íṣẹ́ Òhun Èèlò Sàn “Ifikun Ìyè Owó-Orí (VAT)” To Pọju Ni Q2, 2022
Àwọn ilé-ìṣẹ ohùn eelo ló sàn owo-ori tó pọ̀jù sí àpò ìjọba pẹlú ìyè tí kò dín ni N118.8b, to jẹ ida 33.08 ọgọrùn, ni ipele ìdá-keji (Q2) 2022.
Èyí wà nínú ijabọ Àjọ tí Orílẹ-èdè yíì tí Ìṣirò (National Bureau of Statistics) lórí, “…