Take a fresh look at your lifestyle.

Ìbásepọ̀ Ọrọ̀ Ajé Wáyé Láàrin Orílẹ̀ Èdè Russia Ati India

0 65

Orílẹ̀ èdè Rusia àti India ti parí gbogbo ètò láti se  àfikún àti ìgbélárugẹ fún ìbásepọ̀ lórí ètò ọrọ̀ ajé, ohun àmúsagbára láàrin ara wọn

Eléyìí jẹyọ lẹ́yìn ìpàdé tí ó wáyé láàrin àrẹ orílẹ̀ èdè Russia, Vadimir Putin àti olórí orílẹ̀ èdè India, Narendra Modi ní ìlú Uzebekitan.

Ìbásepọ̀ lórí káràkátà ajílẹ̀ pẹ̀lú àwọn ohun èèlò míràn, léyìí tí orílẹ̀ èdè Indian sì fẹ́ fi ọwọ́ sí ìbásepọ̀ ọlọ́dún mẹ́ta, bí otìlẹ́ jẹ́ pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn orílẹ̀ èdè àgbáyé kò Orílẹ̀ èdè Russia àti india ti parí gbogbo ètò láti se àfukún àti ìgbélárugẹ ìbásepọ̀ lórí ètò ọrọ̀ ajé, ohun àmúsagbára láàrin ara wọn. fẹ́ se àsepọ̀ pèlú oŕilẹ̀ èdè Russia.

 

Gbogbo agbára láti bu ọwọ́ lu ìwe àdéhùn náà j́así pàbó, látàrí àkọlù tí orílẹ̀ èdè Russia se sí orílẹ̀ èdè Ukraine, léyìí tí ìrètí sì wà pé àjọsepọ̀ náà yóò wáyé láìpẹ́ jọjọ.

Leave A Reply

Your email address will not be published.