Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ-èdè Nàìjíríà Gbero Làti Pa Ìyè Owo Ti O To Ẹdẹgbẹta Bílíọ̀nù Náírà (N500b) Ni Ọdun 2023

0 49

Ìgbìmọ̀ Ibaraẹnisọrọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, NCC ti ṣe àfihàn ètò rẹ̀ láti ṣé ipilẹṣẹ tó jù ẹdẹgbẹta biliọnu náírà (N500b) ní ọdún 2023 nípasẹ 5G spectrum.

Igbákejì Alága Alase tí NCC, Ọjọgbọn Umar Danbatta, fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ ni Abùjá, Olú-ìlú Nàìjíríà ní ìpàdé ibaraẹnisọrọ lórí 2023-2025 Medium-Term Expenditure Framework , MTEF, àti Fiscal Strategy Papers , FSP ètò náà ló wáyé ní ipasẹ̀ Ìgbìmọ̀ Aṣojú Ṣofin ẹka ti Ìṣúná owo lórílẹ̀ èdè yìí

Danbatta sò pé owó yóò wọlé nípa títà 5G spectrum méjì ní ọdún 2023.
O tún fi hàn pé NCC ti ṣe ìgbà le ẹtadinlọgọta bílíọ̀nù náírà (N257b) ní Q1 tí 2022, nígbà tí o din díẹ ni ìgbà bílíọ̀nù náírà (N195b) tí a fi ránṣẹ́ sí àpò owó ìjọ̀ba.

Ọgá NCC náà ṣàlàyé pé láti oṣù kẹrin sí oṣù kẹjọ, bílíọ̀nù mejidinlaadọrun náírà (N318 billion) tí jáde nígbà tí a sì fi Ìgbà lè mẹrinla bílíọ̀nù náírà (N214) ranse.

Gẹgẹ bí Danbatta ṣé sọ, owó náà là ti rí nípa títa 5G spectrum méjì tí ìyèérẹ̀ jẹ́ $263 mílíọ̀nù ati $273 mílíọ̀nù owó o kéré.

“NCC láti 2017 sí 2021 tí tún fí ẹgbẹrin din díẹ billion náírà (N799) a tí fí irinwo le díẹ̀ billion náírà (N423) ránṣẹ́ sí ìjọba.

“Ida mẹta ọgọrùn ni ero awon (75%) ni ọdun 2025. Tí àwọn sí ní ìrètí ìdá méjì ọgọrùn ni òpin ọdún 2022.

Ọjọgbọn Danbatta gbà àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nímọ̀ràn láti ló nọ́mbà ìpè pajawiri 112 lati fí lédè ìjàmbá iná, ìjàmbá mọto, ati bẹẹbẹ lọ ati nọmba ọfẹ kan, 622, lati ṣé ifisun àwọn ẹdùn ọkàn wọ́n lórí àwọn ọran tí o jẹmọ́ ìpè.

Alága ìgbìmọ̀ náà, Aṣòfin Olamilekan Adeola, sọ pé Ile Ìgbìmò Aṣòfin yóò tẹ̀síwájú láti ràn àjọ NCC lọwọ láti mú ìlọsíwájú bá ètò náà.

Lekan orenuga

Leave A Reply

Your email address will not be published.