Take a fresh look at your lifestyle.

Síse Àmójútó Ìpèsè Ohun Èlò Ní Abẹ́lé Se Pàtàkì

0 57

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Anambra, Ọ̀jọ̀gbọ́n Charles Soludo ti pè fún fífi ọwọ́ bàbàrà  mú àwọn ohun èlò tí a pèsè ní abẹ́lé, nítorí pé ó jẹ́ ọ̀nà ìpèsè isẹ́ tí ó sì máa ń mú búrùjí bá ọrọ̀ ajẹ.

 

Gómìnà Soludo pe ìpè yìí níbi àjọ àgbáyé kan, eléyìí tí ó wáyé ní ìlú Awka, ìpínlẹ̀ Anambra ní ọdún 2022.

 

Ó se àfirinlẹ̀ ìpinnu ìjọba láti mú ìdàgbàsókè bá àwùjọ àtipé irú ètò bẹ́ẹ̀ yóò mú ìgbòòrò bá ọrọ̀ ajé orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

Leave A Reply

Your email address will not be published.