Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ

This is a category for Africa news

Ìyàwó Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣé Ìlérí Àtìlẹ́yìn Fún Àwọn Obìnrin Àti Ọdọ

Àyá Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Oluremi Tinubu sọ pé òún tí pinnu látí ṣé ìpolongo, koriya àti ìdásílẹ̀ àwọn àjọṣepọ̀ tí yóò fún àwọn obìnrin àti àwọn ọdọ Nàìjíríà ní àgbàrá láti ṣiṣẹ́. ‎ ‎ O n sọrọ yíi l'àkókò Àpéjọ Gbogbogbò tí…

Ààrẹ Tinubu Gúnlẹ̀ Sí Orílẹ̀-èdè Ethiopia Fún Àpérò Ilẹ̀ Adúláwọ̀

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bọla Ahmed Tinubu ti gúnlẹ̀ sí ìlú Addis Ababa, Ethiopia ní alẹ́ Ọjọ́bọ̀ láti kópa nínú ìpàdé àpérò ilẹ̀ adúláwọ̀ ẹlẹ́ẹ̀kejìdínlógójì irú rẹ̀ pẹ̀lú àwọn akẹgbẹ́ rẹ èyí ti yóò…

Àwọn Aṣojú Ìjọba Ilẹ̀ Áfíríkà Kẹ́dùn Olóògbé Nujoma Pẹ̀lú Nàmíbíà

Ìgbìmọ̀ Àwọn aṣojú orílẹ̀-èdè Áfíríkà tí darapọ̀ mọ́ àwọn yòókù lágbayé láti ṣọfọ ikú Sam Nujoma, Ààrẹ àkọkọ́ ní Orílẹ̀-èdè Namibia lẹyìn òmìnira, tó kú ní ẹní odún márún dín lọgọ́rùn (95). ‎ ‎ Nujoma jẹ́ olókìkí ajá-fẹtọ́-ọmọnìyàn,…

Bísọ́ọ̀bù Àgbà Orílẹ̀-èdè South Africa Tọrọ Àforíjì Látàrí Ẹ̀sùn Ìlòkulò Ọmọdé

Bísọ́ọ̀bù àgbà ti ìlú Cape Town se ìpàdé ní ọjọ́ ìṣẹ́gun lẹ́yìn àgbéyẹ̀wò tí wọ́n rí pé àwọn ìgbìmọ̀ mọ̀ pé ìjọ Anglican ni South Africa kùnà láti sọ fún àwọn ìjọ míràn ewu tó lágbára tó wà níbẹ látàrí ìlòkulò ọmọdé lọ́wọ́…

Àwọn alájọṣepọ̀ ààrẹ Benin fi ẹ̀wọ̀n ogún ọdún gbára lórí ìgbèrò ìfipá gbàjọba

Àwọn arákùnrin méjì kan tí wọ́n súnmọ́ ààrẹ orílẹ̀ - èdè Benin, ti fi ẹ̀wọ̀n ogún ọdún gbára lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n mú wọn lọ́dún tó kọjá lórí ìgbèrò ìfipá gbàjọba lórílẹ̀ èdè náà. Ile Ẹjọ ti n risi ẹṣẹ…
button