Browsing Category
Uncategorized
Ọkọ Ojú-irin Níwọ̀nbá Láti Dín Sun-Kẹrẹ-Fa-Kẹrẹ Kú Lágbègbè Nyanyan-Maraba
Gómìnà Nasarawa Abdullahi Sule, so pé ìjọba yóò pèsè Ọkọ oju-irin Alabọdé láti Àpò, Abùjá sì Keffi, Nasarawa láti din sun-kẹrẹ-fa-kẹrẹ kú ní òpópónà to ja geere.
Sule jẹ kí eleyi di mímọ níbi ìpolongo ìdìbò…
Olùdíje ipò ààrẹ fún ẹgbẹ́ SDP ṣe ìlérí láti kojú ìṣòro Nàìjíríà
Olùdíje ipò ààrẹ fún ẹgbẹ́ Social Democratic Party, SDP, sọ pé òun ní agbára láti kojú àwọn ìṣòro tí ó ń kojú àwọn ọmọ Nàìjíríà ní orílẹ̀-èdè náà.
Ọmọ Ọba Adewọle sọ pe pupọ ninu awọn italaya ti Naijiria…
Àjọ NGO Pè Fún Ìpè Àlààfíà Ní Gbogbo Orílẹ̀ Èdè
Àjọ tí kìí ṣe ti Ìjọba, the International Society of Media in Public Health (ISMPH) ti rọ gbogb àgbáyé láti jẹ́kí àlààfíà jọba. Ó sọ pé àlààfíà jẹ́ ìgbìyànjú àpapọ̀, kí a gba àlààfíà láàyè.…
Oǹkọrin orilẹ èdè Nàìjíríà, Yemi Alade Gbé Àwo orin Tuntun Kan Jáde
Gbajúmò Olórin Afrobeats Nàìjíríà kan, Yemi Alade ti kọ orin tó gbé àdídùn Jamaican Dancehall artist Jáde nínú àwo orin tó pè ní ‘Bubble It’.
Orin náà tí ó dín díẹ̀ ní ìṣẹ́jú mẹ́ta ló jáde ní ọjó kẹrìndínlógún oṣù kẹsàn án…
Ìjọba Nàìjíríà Fi Àwọn Ohùn Èlò Fún Ilé Ẹ̀kọ́ Ọ̀gbìn Lẹ́lẹ̀
Minisita Ọgbin Àti Ìdàgbàsókè Ìgbèríko, Dọ́kítà Mohammad Abubakar, tì ṣé ìfilọ́lẹ̀ Ibùgbé àwọn Akẹkọọ àti ile ìṣẹ…
Ilé-Ẹjọ́ South Africa Dá Ilé Isẹ́ Shell Dúró Láti Wa Epo Kùsà
Ilé-ẹjọ́ South Africa kan ti fagilé àṣẹ rẹ̀ àkọ́kọ́ tó fún ilé isẹ́ Shell láti ṣàwárí epo àti afẹ́fẹ́ gáàsì ní agbègbè rẹ̀ tí ó se iyebíye.
Èyí wá bí ìṣẹ́gun ńlá fún àwọn onímọ̀-àyíká àti…
Ààrẹ Buhari rọ àwọn olóṣèlú láti jékí ọ̀rọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ wọ́n lógún
Ààrẹ Muhammadu Buhari ti rọ àwọn aṣáájú òṣèlú lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti dúró ṣinṣin kí wọ́n sì gbé ànfàní orílẹ̀-èdè náà lárugẹ
Aarẹ Buhari sọ èyí nígbà tí o gba àwọn alága ìpínlẹ̀ tẹlẹ rí ti ẹgbẹ́ Congress for Progressive Change…
Eid-El-Kabir: Ẹjẹ́ kí á fi ìfẹ́ bárawa lò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà: Ààrẹ Buhari
Ààrẹ Muhammadu Buhari késí àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti jẹ́kí ànfàní orílẹ̀-èdè kó jẹwọ́n lógún, kósì lékè àwọn ìwà ìmọtara-ẹni-nìkan.
Nínú ọ̀rọ̀ Eid-el Kabir rẹẹ̀ sí àwọn Mùsùlùmí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà…
Bọla Tinubu Ní Ìpàdé Pẹ̀lú Àwọn Gómìnà APC
Nínú ìpàdé tí ó wáyé ní ìlú Abuja, olóyè kàbìtì kan nínú ẹgbẹ́ òsèlú, All Progressives Congress, APC, Ọ̀gbẹ́ni Bola Ahmed Tinubu ti fi ìpinnu rẹ̀ hàn fún àwọn gómìnà ẹgbẹ́ náà láti díje fún ipò ààrẹ.…
Ilẹ́ Isẹ́ Ọmọ Ogun Nàìjíríà Ti Se Àkọsílẹ̀ Àseyọrí Ìkọlù Pẹ̀lu Àwọn Boko Haram/ISWAP
Ile Isẹ ọmọ ogun Naijiria sọ pe ikọlu ti nlọ lọwọ nipasẹ awọn ọmọ ogun Naijira ti a mọ si "Operation Desert Sanity" ti ṣe akọsilẹ isẹ ribiribi miiran latari ikọlu ti wọn ni pẹlu ọpọlọpọ awọn onijagidijagan ISWAP/Boko Haram ni ayika…