Browsing Category
ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GBÌN
Ọrọ̀ Ajé Àgbọn: Ipinlẹ Anambra Ṣiṣẹ́ Pọ̀ Pẹ̀lú Àwọn Adarí Agbègbè
Ìjọba Ipinle Anambra yóò ṣe iṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú adarí àwọn agbègbè láti ri pé wọ́n pín irúgbìn èso igi àgbọn àti ọ̀pẹ fún ilé kọ̀ọ̀kan tó nílò rẹ̀ jùlọ ní ìpínlẹ̀ náà.
Nípa àjọṣepọ̀ yìí, ìmúsẹ ọrọ̀ ajé tó lọ́ọ̀rìn yóò ṣeéṣe.…
Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bu Ọwọ́ Lu Ìlànà Tuntun Lórí Ìmúgbóòrò Iṣẹ́ Àgbẹ̀
Mínísítà fún iṣẹ́ àgbẹ àti ìdàgbàsókè Ìgbèríko, Mohammed Abubakar, sọ pé ìjọba àpapọ̀ ti bu ọwọ́ lu ìlànà tuntun lórí ètò ìmúgbóòrò iṣẹ́ àgbẹ̀ láti ri pé iṣẹ́ àgbẹ̀ tẹ̀síwájú ní ẹ̀ka ìmọ̀ ẹ̀rọ, kí oúnjẹ leè pọ̀ tabua ní orílẹ̀-èdè…
Àwọn Àgbẹ Ìlú Kano Kó Irè Oko Yanturu Ní Àkókò Ọ̀dá Òjò
Àwọn àgbẹ̀ ni ìletò Kanwa, abúlé kan tí kò jìnà púpọ̀ sí ìlú Kano ti kó ọ̀pọ̀ irè oko yanturu látàrí ẹ̀fọ́ gbígbìn.
Ọ̀pọ̀ omi adágún yí abúlé náà po tí eléyìí sì fún àwọn àgbẹ̀ ní ànfààní ẹ̀fọ́ bíi lẹ́tùsì, tòmátì, pòtátò àti…
Orílẹ̀ Èdè France Se Ìrànlọ́wọ́ Owó Fún Ìdàgbàsókè Ètò Ọ̀gbìn Ní Nàìjíríà
Ìjọba orílẹ̀ èdè France ti mú ìgbòòrò bá ètò ọ̀gbìn ní orílẹ̀ èdè Nàìjìríà pẹ̀lú pípèsè owó tí ó lé mílíọ̀nù kan owó ilẹ̀ òkèèrè (1.2m Euro). Èyí tí ìrètí wà pé yóò mú àlékún bá ìpèsè…
Mínísítà Ìlú Abuja Sọ Ayé Di Gbẹdẹmukẹ Látàrí Pípèsè Ilẹ̀ Ọlọ́ràá Fún Ètò Ọ̀gbìn
Mínísítà olú Ìlu Nàìjíríà Malam Muhammed Musa Bello ti jẹ́jẹ̀ẹ́ ìbásepọ̀ tí ó múná dóko pẹ̀lú àjọ tí ó ń se àmójútò ilẹ̀ fún ìpèsè ohun ọ̀gbìn tí ó dára.
Mínísítà, ẹni tí akọ̀wé…
Àkókò Ọyẹ́ Kó Ìpalára Bá Ọ̀sìn Adìẹ Ní Ìpínlẹ̀ Plateau
Ẹgbẹ́ àgbẹ̀ ọ̀sìn Adìẹ ti ìpínlẹ̀ Plateau, orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ti fi ẹ̀dùn ọkàn rẹ̀ hàn látàrí àwọn ìsòro tí ẹgbẹ́ náà dojú kọ ní àsìkò òtútù.
Alága ẹgbẹ́ náà Johnson Baguda sọ pé àsìkò…
Orílè-èdè Senegal Gbà Àlejò Ààrẹ Nigeria Fún Àpéjọ Tó Dá Lórí Ìṣẹ́-Ọ̀gbìn
Ààrẹ Muhammadu Buhari tí dé sí Dakar, Olú-ìlú Senegal, lori àpéjọ ẹlẹẹkeji irú rẹ̀, tí "Dakar International Conference on Agriculture."
Ààrẹ Buhari ló fí ìlú Èkó sílẹ̀ lọ́ sí orílẹ̀-èdè Senegal lọ́jọ́ Ìṣẹgun lẹ́yìn àbẹ̀wò oníṣẹ́…
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Yóò Lọ Ṣí Ìlú Dakar Fún Ìpàdé Lórí Ètò Ọ̀gbin
Ààrẹ Muhammadu Buhari yóò kúrò ní ìlú Èkó lọ sí Orílẹ̀-èdè Sẹ́nẹ́gà ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun fún ìpàdé elẹ́kejì irú rẹ̀ ti àgbáyé lórí ètò ọ̀gbìn.
Ààrẹ Macky Sall ti ilẹ̀ Sẹ́nẹ́gà tó tún jẹ́ alága àgbáríjọpọ̀ Ilẹ̀ Adúláwọ̀ ni…
Olùdarí Àjọ FABDA Pè Fún Àtúnṣe Ẹ̀ka Ètò Ọ̀gbìn
Olùdarí àjọ Fisheries and Aquaculture Business Development Agency (FABDA), Emeka Illoghalu, ti Ìpínlè Anambra ti pè fún àtúnṣe ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn ní gbogbo ìpínlẹ̀ àti ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lápapọ̀ ní wàrànsesà. Eléyìí yóò mú kí…
Ìjọba Nàìjíríà Gbèrò Láti Fẹ́ Àwọn Òpópó-ònà Ìgbèríko Àtí Ìṣẹ́ Àgbẹ̀ Ní Gbogbo Ìpínlẹ̀ Orílẹ̀-èdè…
Ìjọba Nàìjíríà sọ pé òun ń gbèrò látí fẹ́ òpópó-ònà ìgbèríko àti ìtàjà iṣẹ́ àgbẹ̀ (Rural Access and Agricultural Marketing Projects RAAMP), ní gbogbo ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì tí àjọ náà.
Alàkóso ìṣẹ́ àkànṣe náà tí Orílẹ̀-èdè yìí…