Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Nàìjíríà Gbèrò Láti Fẹ́ Àwọn Òpópó-ònà Ìgbèríko Àtí Ìṣẹ́ Àgbẹ̀ Ní Gbogbo Ìpínlẹ̀ Orílẹ̀-èdè Náà

0 224

Ìjọba Nàìjíríà sọ pé òun ń gbèrò látí fẹ́ òpópó-ònà ìgbèríko àti ìtàjà iṣẹ́ àgbẹ̀ (Rural Access and Agricultural Marketing Projects RAAMP), ní gbogbo ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì tí àjọ náà.

Alàkóso ìṣẹ́ àkànṣe náà tí Orílẹ̀-èdè yìí (RAAMP), Ọ̀gbẹ́ni Aminu Mohammed sọ èyí làkókò tí àjọ ṣé idanilẹkọ fún àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ ní Calabar, Ìpínlẹ̀ Cross River.

Èrò àjọ náà ní látí pèsè àwọn òpópó-ònà tó wọlé ní àwọn ìgbèríko látí ṣé alekun ìtàjà ọ̀gbìn.

Ó ṣé àfihàn ìdùnnú rẹ̀ lórí bí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ wọ́n ṣé ń gbórò sí ní gbogbo ìpínlẹ̀ orílẹ̀-èdè. Ó tún tẹnumọ pé àwọn àṣeyọrí tí a tí ní látí ìbẹrẹ iṣẹ́ náà ní ọdún 2008 ní Cross River àti Kaduna ṣé ọnà fún ìdàgbàsókè rẹ̀.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Cross River, Ben Ayade kesi àwọn òṣìṣẹ́ tí iṣẹ́ àkànṣe náà látí má fí ṣé ẹlẹyàmẹ̀yà, ẹsìn tàbí òṣèlú níbí iṣẹ́ wọ́n.

Gómìnà Ayade ṣàpèjúwe RAAMP gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ àkànṣe tó lágbára látí yí ìgbésí ayé pàdà sí dáadáa, pàápàá jùlọ àwọn olùgbé ìgbèríko. Dókítà Inyang Asibong, Kọmisọna fún ètò ókéré ìpínlẹ̀ náà ló ṣoju Gómìnà.

Ilé ifowopamọ Àgbáyé rọ̀ olórí ẹgbẹ́ náà, Ọ̀gbẹ́ni Olatunji Ahmed látí fí ọkàn bálẹ̀ lórí ìpenija èyí k’eyi lórí iṣẹ́ àkànṣe náà.

Àwọn òṣìṣẹ́ náà ní á kọ̀ lẹkọ lórí ìṣàkóso iṣẹ́ àgbéṣe, àtí bẹ́ẹ́bẹ́ lọ̀.

Lekan Orenuga

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button