Browsing Category
ÌRÒYÌN ÀṢÀ ÀTI ÌṢE YORÙBÁ
This is a category for culture and life news
Olórí Òṣìṣẹ́ Ààrẹ Gbà Oyè Ìbílẹ̀ Tintun Ní Nasarawa
Oyè ìbílẹ̀ tuntun gẹ́gẹ́bí aláàbò Ọba – “Zanna Yawu Dima ti Laffan Bare -Bari,” ní a tí fún Olórí Òṣìṣẹ́ Ààrẹ Muhammadu Buhari, Ọjọgbọn Ibrahim Gambari, ní Ààfin Emir tí Lafia, Ìpínlẹ̀ Nasarawa, Àríwá aaringbungbun Nàìjíríà.
Emir tí…
Ìpàtẹ Ọjà Àṣà Gbogbo Àgbáyé Ọdún 2022.
Ilé-iṣẹ́ Ìjọba tó mójútó ìròyìn, àṣà àti ìṣe, tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, pèlú olùgbọ̀wọ́ àjọ àfihàn aṣa ati iṣẹ ni àgbáyé, ti bèrè ètò àfihàn aṣa àti iṣẹ ni ọjọ́ Isẹgun, ọjọ kàrún, yóò sì parí ní ọjọ́ kẹtala oṣù kẹsán ọdún 2022 ni gbọgán Amphi…
Olúbàdàn Ilẹ̀ Ìbàdàn fi àsìkò ọdún Egúngún tó ń lọ lọ́wọ́ ní ìlú Ìbàdàn gbàdúrà fún àlàáfíà àti…
Olúbàdàn Ilẹ̀ Ìbàdàn, Ọba Olalekan Balogun, Alli Okunmade II ti fi àsìkò ọdún Egúngún tó tí bẹ̀rẹ̀ ní igun mẹrẹrin ìlú Ìbàdàn gbàdúrà fún àlàáfíà àti ìṣọ̀kan orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Ọdún Egúngún eléyìí tó má n wáyé lọdọọdun…
Olúbàdàn ilẹ̀ Ìbàdàn kìlọ̀ fún àwọn eégún ṣáájú ọdún Egúngún tó ń bọ̀.
Olúbàdàn ilẹ̀ Ìbàdàn, Ọba Olalekan Balogun, Alli-Okunmade II ti tẹ̀ẹ́ mọ́ gbogbo àwọn tí yóò kópa nínú ọdún Egúngún tí ọdún yìí, eléyìí tí yóò bèrè ní ọjọ́ Ajé (27/06/2022) láti yàgò fún ìwà ipanle eléyìí tó sábà máa ń wáyé.
Ọba…
Ìgbìmọ̀ Ọmọ bíbí Ilẹ̀ Ìbàdàn ti bẹ̀rẹ̀ ètò láti yọ ọwọ́ ìjọba tàbí òṣèlú kúrò nínú jíjẹ oyè àti Ọba…
Ìgbìmọ̀ Ọmọ bíbí Ilẹ̀ Ìbàdàn ( Central Council of Ibadan Indigenes) ti jẹ́ kí ó di mimọ̀ pé, òun ti bẹ̀rẹ̀ ètò láti ṣe atunto eléyìí tí yóò yọ ọwọ́ kilanko ìjọba tàbí òṣèlú kúrò nínú jíjẹ oyè àti Ọba ní ìlú Ìbàdàn ní ọ̀nà láti mú iyì àti…
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ rọ àwọn ọlọ́kadà láti gba nọ́mbà ìdánimọ̀ sí ọ̀kadà wọn
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti sọ́ di mímọ̀ pé ètò tí nlọ láti bẹrẹ ìforúkọsílẹ àti pínpín nọmba ìdánimọ̀ fún gbogbo ẹni tí ó n fi alupupu "okada" ṣe Ajé ìgboro ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Kọmísánà fún Ètò Ìṣúná àti Ìṣirò ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ọ̀jọ̀gbọ́n…
Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano, Abdullahi Umar Ganduje àti ìyàwó rẹ̀ jẹ oyè ‘Ààrẹ Fìwàjoyè’ àti…
Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano, Abdullahi Umar Ganduje ti pè fún èmí ìsọ̀kan àti ìbágbépọ̀ láàrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Ganduje ló sọ ọ̀rọ̀ yìí di mímọ̀ lásìkò tí Olúbàdàn Ilé Ìbàdàn, Ọba Lekan Balogun, Alli Okunmade II fi òun àti aya rẹ̀…
Ayẹyẹ Ọjọ́ Ìjọba Tiwantiwa Parí Pẹ̀lú Àrà Àti Ẹ̀yẹ Ní Ìlú Abuja
Àwọn ètò pàtàkì tí a là sílẹ̀ fún ayẹyẹ ọjọ́ ìjọba tiwantiwa ti ọdún yìí ti parí pẹ̀lú àrà àti ẹ̀yẹ ní orí pápá Eagle Square, ní ìlú Abuja.
Aarẹ Muhammadu Buhari, ẹni to jẹ alejo pataki nibi ayẹyẹ náà wa ni…
Olúbàdàn ilé Ìbàdàn, gba àwọn olóyè tó gba ìgbéga níyànjú.
Olúbàdàn ilé Ìbàdàn, Ọba Lekan Balogun gba àwọn olóyè àgbà tó ṣẹ̀ gba ìgbéga níyànjú.Olúbàdàn ilé Ìbàdàn, Ọba Lekan Balogun, Alli Okunmade II ti gba àwọn olóyè àgbà márùn tí wọ́n gba ìgbéga láti ìpele kan sí òmíràn níyànjú láti rí ara wọn…
Mí ò ní yẹ Ìlànà ọba jíjẹ tò ti wà ní àkọsílẹ wo ni ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́.-Seyi Makinde
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti sọ́ di mímọ̀ wípé òun ò ní ye Ìlànà àń f'obá jẹ tò ti wà ní àkọsílẹ wò nígbà tí àsìkò bá tó láti yan ẹni tí yóò jẹ Aláàfin.
Gómìnà Seyi Makinde ló sọ ọ̀rọ̀ yìí di mímọ̀ lásìkò tí ìjọba ìpínlẹ̀…