Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ
This is a category for business news
Ìgbésẹ̀ Ààrẹ Tinubu Lórí Ètò Ọrọ̀ Ajé Yóò So Eso Rere Fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà-…
Gómìnà Ìpínlẹ Enugu, Peter Mbah ti sàpèjúwe ìgbésẹ̀ Ààrẹ Tinubu lórí ètò ọrọ̀ ajé gẹ́gẹ́ bí èyí tí ó tọ́, tí yóò sì so èso rere fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Mbah tẹ̀síwájú pé ìgbésẹ̀ láti ní…
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Tún Yan Mele Kyari Gẹ́gẹ́ Bi Ọ̀gá Àgbà Pátápátá Fún Ilé iṣé NNPCL.
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bola Tinubu ti Yan Mele Kyari ni ìgbà Kejì gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá àgbà pátápátá fún ilé iṣé tó ń mójú tó ọ̀rọ̀ Epo rọ̀bì ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà NNPCL.
Ààrẹ tún buwọ́lù àwọn alábàáni ṣiṣẹ́ pọ̀ fún ilé iṣé náà
Ààrẹ Yan…
Ètò Ẹ̀yáwó Fún Àwọn Ọmọ Ilé Ẹ̀kọ́ Yóò Gbérasọ Láìpé Jọjọ- Gbajabiamila
Alákòóso iṣẹ́ Ààrẹ, Fẹmi Gbajabiamila ti salaye pe ijọba apapọ ń là kààkà láti ri daju pe ètò ẹ̀yáwó fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gbérasọ ni osu kíní, ọdún 2024
O tẹsiwaju pe eto naa yoo fun awọn akẹkọọ ni anfaani…
Ìgbákejì Ààrẹ Shettima Ṣé Alága Ìpàdé Ìgbìmò Ètò Ọ̀rọ̀-ajé Tí Orílẹ̀-èdè
Ìgbákejì Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Kashim Shettima tí n ṣé alákóso ìpàdé tí Ìgbìmọ̀ Ètò Ọ̀rọ̀-ajé 'National Economic Council (NEC).'
Ìpàdé náà, tó bẹ̀rẹ̀ ní 10:25 GMT, ń wáyé ní ìyèwù ìgbìmọ̀ tí Ilé-iṣẹ́ Ààrẹ ní Abuja.
Àwọn tí…
COEASU gbóríyìn fún ààrẹ Tinubu fún ìdádúró ìdá ogójì nínú ọgọ́rùn ún
Ẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ni ti ilé-ìwé olùkọ́ni, COEASU, ti gbóríyìn fún ààrẹ, Bọla Ahmed Tinubu fún bí ó ṣe lo ọgbọ́n tí ó sì dá ìlànà tí ó ní kí àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga lórílẹ̀-èdè máa san ìdá ogójì nínú ìdá…
Orílẹ̀-èdè China Àti Saudi Buwọ́lu Ìwé Àdéhùn Fún Ìpààrọ̀ Owó
Ilé Ìfowópamọ́ Àpapọ̀ ti Orílẹ̀-èdè China àti ojúgbà rẹ̀ ní Orílẹ̀-èdè Saudi Arabia ti fi ọwọ́ sí ìwé àdéhùn láti máa fi owó Orílẹ̀-èdè méjéèjì pààrọ̀ arawọn
Àdéhùn náà yóò lo ọdún mẹ́ta…
Àwọn Ọmọ Orílẹ̀-ede Nàìjíríà Ti Gbáradì Láti Gbàlejò Olùdókoòwò Ilẹ̀ Òkèèrè-…
Ààrẹ Oriĺẹ̀-èdè Nàìjíríà Bọla Ahmed Tinubu ti sàpèjúwe àwọn Ọmọ Orí́lẹ̀-èdè Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí ọ̀jọ̀gbọ́n, ọlọ́pọlọ pípé, olùfarajì tí ó le è figa-gbága pẹ̀lú ojúgbà rẹ̀ ní àgbáyé
Ààrẹ fi…
Ilé Ẹjọ́ Fi Emefiele Sí Àhámọ́, Ó Sún Ìgbẹ́jọ́ Síwájú
Ilé Ẹjọ́ Gíga tí ó fi ìlú Abuja se ibùjókòó ti pàsẹ kí gómìnà Ilé Ìfowópamọ́ Àpapọ̀ tẹ́lẹ̀rí, Godwin Emefiele wà ní Ọgbà Ẹ̀wọ̀n Kuje tí Ilé Ẹjọ́ Yóò fi sèdájọ́ lórí ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ láti dá a sílẹ̀
…
Ìpàdé Ìdókó-òwò Abẹ́lé Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Lókè Okùn Ẹ̀kẹfà: Ọjọ́ Àkọ́kọ́
Níbí ìṣidé ìpàdé àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó wà lókè okùn ẹlẹ́ẹ̀kẹfà irú rẹ̀ '6th Nigeria Diaspora Investment Summit' tó bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kẹtala sí ọjọ́ kẹ́ẹdógún, Oṣù Kọkànlá, Ọdún 2023, ilé-iṣẹ́ tó ń rí sí ọ̀rọ̀ àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè…
Ìpàdé Àpérò Lórí Ètò Ọrọ̀ Ajé Ti Ọdún 2023 Tí Ìrètí Wà Pé Yóò Wáyé Ní…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Gombe ti kéde sísún síwájú ìpàdé àpérò ètò ọrọ̀ ajé ti ọdún 2023 èyí tí ìrètí wà pé yóò wáyé ní ọjọ́ kẹrìndínlógún sí ọjọ́ kẹtàdínlógún osù kọkànlá, ọdún yìí.
Alága…