Ilé Ẹjọ́ Gíga tí ó fi ìlú Abuja se ibùjókòó ti pàsẹ kí gómìnà Ilé Ìfowópamọ́ Àpapọ̀ tẹ́lẹ̀rí, Godwin Emefiele wà ní Ọgbà Ẹ̀wọ̀n Kuje tí Ilé Ẹjọ́ Yóò fi sèdájọ́ lórí ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ láti dá a sílẹ̀
Ilé Ẹjọ́ sún ìjókòó síwájú sí ọjọ́ kejìlélógún, osù kọkànlá láti se ìdájọ́ lórí ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ ìdásílẹ̀ rẹ̀
Adájọ́ Hamza Muazu ni ó pàsẹ fífi Emefiele sí àhámọ́ tí ó sì sún ìjókòó ilé Ẹjọ́ sí ọjọ́ kejìlélógún osù kọkànlá.