Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpàdé Ìdókó-òwò Abẹ́lé Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Lókè Okùn Ẹ̀kẹfà: Ọjọ́ Àkọ́kọ́

0 178

Níbí ìṣidé ìpàdé àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó wà lókè okùn ẹlẹ́ẹ̀kẹfà irú rẹ̀ ‘6th Nigeria Diaspora Investment Summit’ tó bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kẹtala sí ọjọ́ kẹ́ẹdógún, Oṣù Kọkànlá, Ọdún 2023, ilé-iṣẹ́ tó ń rí sí ọ̀rọ̀ àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nilẹ̀ òkèèrè ‘Nigerians in Diaspora Commission (NIDCOM)’ ṣé àfihàn àjọṣepọ̀ náà gẹ́gẹ́ bí òkùnfà ìdàgbàsókè ètò ọrọ̀ ajé Nàìjíríà.

Alága NIDCOM, Dókítà Abike Dabiri-Erewa, sọ pé látí tẹ̀síwájú lórí atunto ètò ọrọ̀ ajé, Orílẹ̀-èdè yìí nílò látí ṣé àjọṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ wá nílẹ̀ Òkèèrè àtí àwọn oludokoowo mìíràn.

Bákan náà, Aṣojú Ìlú Ireland sí Nàìjíríà, Ọgbẹni Peter Ryan, sọ pé orílẹ̀-èdè rẹ̀ tí ṣetán láti ṣé ohunkóhun tó ní ṣé látí ṣé agbega àwọn ọmọ àtí owó Nàìjíríà.

Leave A Reply

Your email address will not be published.

button