Browsing Category
ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ
This is a category for politics news
Ìdájọ́ Ilé Ẹjọ́ Kòtẹ́milọ́rùn: Àjọ Ọlọ́pàá Pèpè Fún Àlàáfíà Àti Ìfọ̀kànbalẹ̀ Ní…
Àjọ Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Nasarawa ti se ìkìlọ̀ fún àwọn alátìlẹyìn ẹgbẹ́ òsèlú láti jìnà sí ìwà tí ó le è da omi àlàáfíà ìlú rú síwájú ìdájọ́ Ilé Ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn tí yóò wáyé ní ìpínlẹ̀ náà…
Atiku Fi Ìdùnnú Hàn Lórí Ìdàgbàsókè Tí Ó Wáyé Ní Ìpínlẹ Adamawa
Igbákejì Ààrẹ tẹ́lẹ̀rí, Atiku Abubakar fi ìdùnnú rẹ̀ hàn látàrí iṣẹ́ ribiribi tí Gómìnà ìpínlẹ̀ Adamawa, Ahmadu Fintiri ń se
Atiku sọ ọ̀rọ̀ náà ní ilé ìgbé rẹ̀, ní ìlú Yola, Ìpínlẹ̀ Adamawa nígbà tí…
Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Jẹ́jẹ̀ẹ́ Àtìlẹyìn Láti Mú Ìdàgbàsókè Bá Ìlú Abuja
Igbákejì Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin, Ọnọrébù Benjamin Okezie sọ pé Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin ti gbáradì láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú Mínísítà tí ń se àkóso Ìlú Abuja, lójúnà àti mú ìdàgbàsókè bá olú ìlú…
Kòsí Nínú Èrò Ìjọba Àpapọ̀ Láti Sọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Di Èyí Tí Yóò Máa Lo…
Ìjọba Àpapọ̀ ti rọ ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjiríà láti jìnà sí ìròyìn kan tí ó ń fò káàkiri nípa pé Ààrẹ Bọla Tinubu ń gbèrò láti sọ Nàìjíríà di Orílẹ̀-èdè tí yóò máa lo ẹgbẹ́ òsèlú kan ṣoso nípa…
Àṣèyege ilé-ẹjọ́ Plateau: APC rọ ẹgbẹ́ láti ṣe jẹ́jẹ́
Ikọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC ti ìpínlẹ̀ Plateau ti rọ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀ láti ṣe àjọyọ̀ ìdájọ́ ilé-ejọ́ lórí ìbò gómìnà níwọ̀nba, láti máá dá wàhálà sílẹ̀.
Alaga rẹ, Oloye Rufus Bature, gba…
Ìdìbò agbègbèTaraba: PDP gbégbá orókè ní gbogbo LGA mẹ́rìndín-lógún
Àwọn Olùdíje fún ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party, PDP ní ìpínlẹ̀ Taraba ti palẹ̀mọ́ gbogbo ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́rìndín-lógún ìpínlẹ̀ náà tán nínú ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ parí ní ìpínlẹ̀ náà.…
Ìgbẹ̀mí ara ẹni: ìjọba Eko rọ àwọn ọkùnrin láti sọ ẹ̀dùn ọkàn wọn síta
Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko ti rọ àwọn ọkùnrin láti pa Àṣà àti máa dákẹ́ dà kí wọ́n ó sì sọ̀rọ̀ síta, láti dáwọ́ èrò ìgbẹ̀mí ara ẹni dúró.
Ìyáàfin Titilọla Vivour-Adeniyi, Akọwe Alaṣẹ, ile-iṣẹ abẹle ati ibalopọ ipa ti…
Èsì Ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kano: Moni Ìgbàgbọ́ Pé Ilé Ẹjọ́ Tó Gajù Lọ Yóò Ṣe Ìdájọ́ Òdodo –…
Ẹni tíì ṣe èèkàn nínú ẹgbẹ́ òṣèlú New Nigeria People's Party (NNPP), Olufemi Ajadi Oguntoyinbo ti fi ọwọ́ sọ̀yà pé ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ (Supreme Court) yóò ṣe ìdájọ òdodo lórí Gomina Ìpínlẹ̀ Kano, Abba Yusuf.
Oguntoyinbo tó jẹ́ bàbá…
Àsọdùn ọ̀rọ̀ ni ohun tí àwọn ènìyàn ń sọ nípa iye owó tí ìjọba àpapọ̀ fẹ́ fi ra ọkọ̀…
Asofin to n soju fun ẹkun Irẹpọ,Orelope ati Ọlọrunsogo ní ipinlẹ Ọyọ, ọmọọba Lateef Ọlaide Mohammed ti ni ko si otitọ nipa ọrọ ti awọn eniyan ń sọ nipa iye owó ti ijọba apapọ fẹ fi ra ọkọ ti awọn asofin fẹ fi maa ṣe isẹ wọn.
wọn…
Bala Ni Gómìnà Ìpínlẹ̀ Bauchi: Ilé Ẹjọ́ Kòtẹ́milọ́rùn Fi Ìdí Ọ̀rọ̀ Múlẹ̀
Ilé Ẹjọ́ Kòtẹ́milọ́rùn tí ó wà ní ìlú Abuja ti fi ìdí ìjáwé olúborí Gómìnà Bala Mohammed ti ẹgbẹ́ òsèlú PDP múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi gómìnà tí wọ́n dìbò yàn fún ìpínlẹ̀ Bauchi
Ilé Ẹjọ́ se Ìdájọ́…