Browsing Category
KÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN
This is a category for featured story
Ìkọlù Àwọn Agbébọn Sí Ọfiisi Ọgbà Ìtọ́jú Ẹranko Àtijọ́: Makinde Ṣèlérí Òpin Sí Irú Ìkọlù Bẹẹ
Látàrí ìṣẹ̀lẹ̀ ìkọlù àwọn agbébọn sí àwọn òṣìṣẹ́ ọgbà ìtọ́jú ẹranko àtijọ ni Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí àwọn ènìyàn agbègbè náà láti ṣe sùúrù.
Ìṣẹ̀lẹ̀ ìkọlù àwọn agbébọn eléyìí ti Alukoro ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, DSP…
Sarkin Hausawa Ìlú Ìbàdàn Gbésẹ̀: Makinde Kẹ́dùn Pẹ̀lú Olúbàdàn Àti Ẹ̀yà Hausa Ní Ìlú Ìbàdàn
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti fi ikú Sarkin Hausawa ìlú Ìbàdàn, Alahji Ali Dahiru Zungeru we àdánù nla.
Gómìnà, ẹni tó fi olóògbé Zungeru wé olólùfẹ́ àlàáfíà àti adarí tó ṣeé gbẹ́kẹ̀lé náà ló bá Olúbàdàn ilẹ̀ Ìbàdàn,…
Ẹgbẹ́ ikọ̀ Agbábóòlù Chelsea Yan Liam Rosenoir Gẹ́gẹ́ Bí Olukọni Àgbà Fún Ẹgbẹ́ Náà
Ẹgbẹ́ Agbábóòlù Chelsea so wí pè Títí di ọdún 2032 ni Rosenior yóò fí wá ni ipo Olukọni àgbà, fun ẹgbẹ́ náà ọ̀rọ̀ yìí jade ní ọjọ́ ìṣẹgun.
Rosenior ló kó ikọ̀ Agbábóòlù Strasbourg ló ṣì Orílẹ̀-èdè European fún ìdíje ṣùgbọ́n ni báyìí o ti…
Ẹ jẹ́ kí Àlàáfíà Joba Lásìkò Ìdìbò Ọdún 2027: Gómìnà Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom
Gómìnà ìpínlẹ̀ Akwa Ibom Olùṣọ Àgùntàn Uma Eno ti pe àwọn ará ìlú ati àwọn Olóṣèlú láti jẹ ki Àlàáfíà Joba Lásìkò Ìdìbò Odun 2027.
Gómìnà mu amoran àlàáfíà yìí wa lasiko ti wọn se idupe ọdun tuntun ni gbo gán International Worship ni…
Ẹgbẹ́ Ọmọ Ológun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Tú Àṣírí Àwọn Oníṣẹ́ Láabi Ni Ìpínlẹ̀ Adamawa.
Ẹgbẹ́ Ọmọ Ológun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti wọn n pé ni OPHK ti dènà ìwà ìbàjẹ́ ti yóò mú emi opolopo àwọn ènìyàn ló.
Ọwọ́ ba àwọn ènìyàn mẹjọ, ati àwọn odara meji miran ni inu ọjà Gamboru ni èyí tì wọn fẹ gbà Emi ara wọn ati àwọn ènìyàn…
Ẹgbẹ́ Ọmọ Ológun Orílẹ̀-èdè Ṣe Ìfilọ́lẹ̀ ìpàdé Fún Ìdanilẹ́ẹ̀kọ́ Odún 2026.
Ẹgbẹ́ Ọmọ Ológun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti bẹ̀rẹ̀ ìpàdé fún Ìdanilẹ́ẹ̀kọ́ ti odún 2026 pẹ̀lú ètò ati ìlànà ẹ̀kọ́ ẹyi ti àjọ TRADOC ṣe agbáterù re.
Nígbà ti o n sọ̀rọ̀ níbi ayẹyẹ náà ọgá àgbà pátá fún ẹgbẹ́ Ọmọ Ológun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà…
Ètò ìṣúná owó Ọdún 2026 Jẹ́ Àtìlẹ́yìn Nlá Fún Ààrẹ Tinubu: Mínísítà Fún Ọ̀rọ̀ Tó Ńlọ
Mínísítà fún ọ̀rọ̀ tó nlọ Alhaji Mohammed Idris so wí pè ẹ̀tọ̀ ìṣúná owó Ọdún 2026 jẹ ohun tí wọ́n fi ọgbọ́n àti làákàyè gbé kalẹ fún àtìlẹ́yìn ijoba Ààrẹ Tinubu.
Nínú ọ̀rọ̀ tó jáde láti ẹnu Mallam Rabiu Ibrahim to jẹ ìgbà Kejì pàtàkì…
Ikọ̀ Super Super Eagles Lu Ikọ̀ Mozambique Ní Àlùbami Pẹ̀lú Ayò Mẹ́rin Sí Òdo(4-0) Peregedé Sì Ipele…
Ikọ̀ Super Eagles borí ìdíje wọn ní papa isere Fes nígbà ti wọn lù alútakò wọn, Mozambique bí ẹní lu aṣọ òfì pẹ̀lú ayò mẹ́rin si òdo(4-0) tí wọ́n sì peregedé sì quarter-finals ìdíje AFCON ọdún 2025.
Ògbóntàrigi agbábọ́ọ̀lù…
Ilé ẹjọ́ tó gajù lọ ní Guinea fìdí àṣeyege ìbò Ààrẹ Doumbouya muĺẹ̀
Ilé ẹjọ́ tó gajù lọ ní Guinea ti fìdí àṣeyege ìbò Ààrẹ Olóyè Mamady Doumbouya muĺẹ̀, pẹ̀lu ìbò ìdá mẹ́rìndín-láàdọ́rùn ún àti díẹ̀.
Eyi jeyọ ninu esi ti wọn kede ni ọsẹ to kọja, lẹyin ibo ọjọ kejidin-lọgbọn ti…
Ecowas Pé Fún Ọwọ̀ Lórí Ìjọba Venezuela
Àwùjọ Ètò-ọrọ-àjé tí Àwọn Orílẹ̀-èdè Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà (ECOWAS) sọ pé àwọn wó idagbasoke túntún tí ń lọ́ ní Orílẹ̀-èdè Venezuela pẹ̀lú àníyàn nlá.
Gbólóhùn kan lati ọdọ Igbimọ ECOWAS sọ pe òun mọ́ pé ẹtọ wà láti kojú awọn òun…