Browsing Category
KÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN
This is a category for featured story
Ètò Ìlera Ọ̀fẹ́: Makinde Ṣíde Ìfilọ́lẹ̀ Ìlera Ọ̀fẹ́ Ní Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá/Ìlà-Oòrùn Ìbàdàn.
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti jẹ ko di mímọ̀ pé ìṣèjọba òun yóò tẹ síwájú láti máa pèsè ètò ìlera lójúnà àti ri dájú pé ará ìlú wa ni ìlera pípé eléyìí tí yóò mú kí ọrọ̀ ajé rú gọ́gọ́ síi, ti ìṣẹ yóò sì dínkù ni àwùjọ.
Makibde…
Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ Nàìjíríà Buwọ́lù Tírílíọ̀nù Kán Lè Díẹ̀ Fún Àwọn Iṣẹ́ Àmáyédẹrùn Tí Orílẹ̀-èdè
Ìgbìmọ̀ àwọn Aláṣẹ tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (FEC) tí fọwọ́sí tírílíọ̀nù kán lè díẹ̀ Náírà (N1.202) fún àwọn iṣẹ́ àkànṣe àmáyédẹrùn orílẹ̀-èdè pàtàkì bí iná mọna-mọna, Pápákọ́ Òfurufú, àti àwọn iṣẹ́ òpópó-ònà tí nlọ lọwọ́.
Ìgbésẹ pàtàkì…
Àwọn Adarí Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Ṣetán Ìpàdé Ìgbàlà Ọmọ Ẹgbẹ́ Kúrò Lọ́wọ́ Ìsákiri Lọ Inú Ẹgbẹ́ Òṣèlú Míràn
Gómìnà àti gómìnà tẹ́lẹ̀rí lábẹ́ òṣèlú ẹgbẹ́ People’s Democratic Party (PDP) péjọpọ̀ si ìlú Abuja láti wà ọ̀nà àbáyọ sì ìsákiri àwọn ọmọ ẹgbẹ lọ sin ẹgbẹ́ òṣèlú mìíràn.
Àwọn to peju pèsè síbi ìpàde náà láti ri,…
Ikọ̀ Ranger Lu Ikọ̀ Katsina Ní Àlùbami Ayò Mẹ́rin Sí Òdo 4-0
Ní ọjọ́ Àìkú, ikọ̀ Rangers International FC ti ìlú Enugu lu ikọ̀ Katsina United FC ni àlùbami ayò mẹrin sì Odo (4-0) ti wọn kò sì leè ru tùú láti tilẹ̀ da ọkàn soso padà nínú ìdíje ọlọ́sẹ̀ kẹrìndínlógójì ti - Nigeria Premier…
Àjọ NiDCOM Gbósùbà Fún Ọ̀dọ́mọdébìnrin Tó Gbégbá Orókè Níbi Ìdíje Ẹ̀kọ Spelling Bee
Alága àjọ Nigerians in Diaspora Commission, NiDCOM, Dókítà Abike Dabiri-Erewa gbósùbà ràbàndẹ̀ fún odomobirin ọmọ ọdún Mejila, Amazing-Grace Ahuoyiza Ebiebi Salami tó gbégbá orókè níbi iside ìdíje ẹkọ Spelling Bee In Nigeria…
Ilé-iṣẹ́ Apínánká Sudan Ṣe Àṣeyọrí Didá Iná Padà
Ilé iṣẹ apínánká orilẹ̀-ède Sudan pẹlu ti awon ọmọ ogún Civil Defense Forces ílẹ náà ti ṣe aseyege pipa iná tó sẹ́yọ ní Port Sudan, wọn sì ti bere si ní da ina pada sì àwọn ibi ti kò níná ní orílẹ̀-èdè náà lẹ́yìn Ìkọ̀lù sì wọn…
Mínísítà Múlele Lórí Ìwúlò Àjọṣepọ̀ Ilẹ̀ Òkéere Fún Ìtèsíwájú Ẹ̀ka Ètò Ìwakùsà
Ìgbákejì pataki nípa iroyin sì Mínísítà ìtèsíwájú àwọn ohun alumọni ilẹ̀,Segun Tomori ló gbé eleyi síta.
Dókítà Alake sọ pàtàkì ojuse ìwakùsà nípa ti ìlànà agbaye ní ti àjọ Organisation for Economic Cooperation and…
Mínísítà gbóríyìn fún Ààrẹ bí ó se ka àwọn iṣẹ́ àkànṣe tí yóò ṣíṣọ lójú rẹ̀…
Mínísítà Nàìjíríà fún olú ìlú (FCT), Ọ̀gbẹ́ni Nyesom Wike, ti ṣàlàyé pé Abuja ti rí àyípadà tó lápẹẹrẹ lábẹ́ ìṣàkóso Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu.
Mínísítà sọ eyi di mimọ lasiko abẹwo ibojuto iṣe Akanṣe opopona…
Emir ti ìlú Ìlorin gbàdúrà fún Nàìjíríà, Ààrẹ, Gómìnà Kwara
Emir ti ìlú Ìlorin tí ó tún jẹ́ Alága ìgbìmọ̀ lọ́balọ́ba ní ìpínlẹ̀ Kwara, Arewa Àringbùngbùn Nàìjíríà, Alhaji Ibrahim Sulu-Gambari ti pe ìṣàdúrà pàtàkì fún àlàáfíà àti ìdúróṣinṣin orílẹ̀-èdè, ní…
Ilé ìwòsàn Ìkọ́ni pàtàkì ìwà láláàfíà àwọn òṣìṣẹ́ – CMD
Ọ̀gá Àgba Adarí Ìṣòògùn, CMD, ti gbọ̀ngàn ilé ìwòsàn Ìkọ́ni ti ilé Ẹ̀kọ́ Gí́ga Fáfítì Ọbafemi Awolọwọ , OAUTHC, Ilé-Ifẹ̀, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun , Gúsù- Ilà Oòrùn, Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n John Okeniyi ti ṣàlàyé pé…