Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

KÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN

This is a category for featured story

Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Ní Ìlà Oòrùn Gúsù Ti Kìlọ Látàrí Ìpè Ìpàdé Àwọn Alẹ́nulọ́rọ̀ Tó Jẹ́ Òfegè

Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Ní Ìlà Oòrùn Gúsù ti kìlọ fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀ láti má ka ìpè ipàdé pàjáwìrì àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ ní Abuja sí. Nínú àkọsílẹ̀ ìròyìn kan, alukoro ẹgbẹ́ ní ẹ̀ka ìlà oòrùn gusu, Chigozie Igwe, tẹnumọ…

NGO ní òun ti ní ipa lórí àwọn ènìyàn méjìlé-lọ́gbọ̀n Mílíọ́nù ní abala ìtọ́jú…

Ilé iṣẹ́ tí kìí ṣe tìjọba kan, Nigeria Solidarity Support Fund, NSSF, ti sọ pé òun ti ní ipa lórí àwọn ènìyàn méjìlé-lọ́gbọ̀n Mílíọ́nù ní ọdún mẹ́rin tí òun ti ń ṣiṣẹ́ ní abala ìtọ́jú ìlera lórílẹ̀-èdè.…

Ọ̀sẹ̀ Àṣà Ìlú Ìbàdàn Tí 2025: Makinde Ṣèlérí Láti Fún Àwọn Olórí Ìlú Ní Ẹ̀tọ́ Wọn.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ṣèlérí pé ìṣèjọba òun kò ní fi ẹ̀tọ́ àwọn olórí ìlú dùn wọ́n. Gómìnà ló sọ ọ̀rọ̀ yii di mímọ̀ níbi àṣèkágbá ayẹyẹ ọsẹ̀ àṣà ìlú Ìbàdàn to wáyé ni pápá ìṣeré Obafemi Awolowo, ni agbègbè Òkè-Ado, ni ìlú…

Hajj 2025: Kwara gbé àwọn arìnrìn àjò mímọ́ ikọ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹta ti ẹdẹ̀ẹ́gbẹ̀ta-ó-lé-ọgọ́ta Lọ…

Ikọ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹta àwọn arìnrìn àjò mímọ́ tí ó tó ẹdẹ̀ẹ́gbẹ̀ta -ó -lé -ọgọ́ta láti ìpínlẹ̀ Kwara gbéra lọ sí Saudu Arabia ní ọjọ́ Àbámẹ́ta láti ṣe iṣẹ́ mímọ́, tí ó sì jẹ́ pé ọkọ̀ òfurufú Max ni ó gbé wọn láti…
button