Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ
This is a category for business news
Ìpínlẹ̀ Èkó Ti Fọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lú Àwọn Ilé Ìfowópamọ́ Fún Ìrànlọ́wọ́ Àwọn Obìnrin…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó ti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ilé ìfowópamọ́ mẹ́ta láti se ètò ẹ̀yáwó fún àwọn obìnrin onísòwò ní Ìpínlẹ̀ Èkó
Gẹ́gẹ́ bí ìjọba se sọ, ètò náà yóò mú ìdàgbàsókè bá ọrọ̀…
Ilẹ̀ Ọlọ́ràá Ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Fún Ìdàgbàsókè Oko Òwò- Shettima Pàrọwà Sí…
Ìsàbẹ̀wò igbákejì ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Kashim Shettima ti bẹ̀rẹ̀ sí máa so èso rere nígbà tí àwọn olùdókoòwò ilẹ̀ òkèèrè ti ń fi ìgbáradì wọn hàn láti sàgbékalẹ̀ ìdókoòwò fún ìdàgbàsókè…
Ẹri Dájú Wípé Ààbo Tó Péye Wà Fún Àwọn Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà: Ilé Ìfowópamọ́ Àgbáyé.
Ilé Ìfowópamọ́ Àgbáyé ti ke sí ìjoba àpapọ láti sa ipá wọn, fún ètò Ààbo Tó Péye Fún Àwọn Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Wọ́n ní, àwọn sọ èyí látàrí bí àwọn nkán ṣe di ọ̀wọn gọ́gọ́, tí ó sì ń Ṣe àkóbá fún àwọn ènìyàn pàápàá jùlọ àwọn Ọmọ…
Ramadan: Ọba Nupe rọ àwọn ọlọ́jà láti mówó oúnjẹ wálẹ̀
Alhaji Yahaya Abubakar, tí ó jẹ́ Etsu Nupe, (Ọba àwọn Nupe ní Aríwá Àringbùngbùn Nàìjíríà) ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí àwọn ọlọ́jà lórílẹ̀-èdè láti máá fowó kún owó oúnjẹ àti àwọn èròjà oúnjẹ mìíràn bí oṣù…
Àjọ NDE Ró Àwọn Olùgbé Ìpínlẹ̀ Ebonyi Lágbára
Àjọ Directorate of Employment Empowers, NDE ti ro àwọn Olugbe Ipinle Ebonyi méjìdínniọ́gọ̀sán lagbara pẹlu iṣẹ SME.
Àjọ Directorate of Employment Empowers, NDE ni ipinle Ebonyi ti bẹrẹ iṣẹ ìkọ́ni ati ironilagbara fún àwọn…
Ìpínlẹ̀ Ogun: Igbákejì Shettima Sí Ilé Ìtajà Tuntun Fún Àwọn Ọlọ́jà
Igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Kashim Shettima tí ṣe ìfilọ́lẹ̀ àti àti sí sí ilé ìtàjà tuntun tó wa Asero ni ìlú Abeokuta ti wọn ti tàn Adire , ilé ìtàjà to jẹ ọgọrùn méjì ìbùsọ̀ fún àwọn ènìyàn.
Wọn ni àwọn Olùtajà yóò jẹ ànfààní…
Ìbẹ̀wò Ààrẹ Tinubu Sí Qatar Ní Látí Mú Ìbáṣepọ̀ Orílẹ̀-èdè Méjèèjì Gbòòrò Sí
Ààrẹ tí sọ pé àbẹwò tí Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu sí Qatar ní èròngbà látí mú ifọkanbalẹ ètò ọrọ̀-àjé láàrín Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àtí ìjọba Qatar lágbára sí.
Olùdámọ̀ràn pàtàkì sí Ààrẹ lórí ìròyìn àtí Ìlànà,…
Alága AMAC Sèkìlọ̀ Fún Àwọn Olùsan-Owóorí Láti Jìnà Sí Sísan Owó Sí akoto Ayédèrú
Alága àjọ AMAC, Ọ̀gbẹ́ni Christopher Zakka ti pàrọwà sí àwọn tí ó ń san owó-orí láti san owó sí akoto ìjọba èyí tí àjọ AMAC gbé kalẹ̀
Alága sọ ọ̀rọ̀ náà nígbà tí ó ń bá àwọn akọ̀ròyìn sọ̀rọ̀…
Ìjọba Nàìjíríà Tí Rí Àwọn Ọ̀nà Tí Wọ́n Ń Gbà Kó Oúnjẹ Jáde Lórílẹ̀-èdè Náà
Ìjọba Nàìjíríà sọ pé àwọn ti ṣàwárí ọ̀nà méjìlélọ́gbọ̀n tí wọ́n fi ń kó oúnjẹ kúrò lórílẹ̀-èdè náà lọ́ àwọn Orílẹ̀-èdè mìíràn.
Ìgbákejì Ààrẹ Kashim Shettima sọ pé ní ọ̀gànjọ́ òru ọjọ́ Aiku, àwọn ọkọ̀ nlá márùnlélógójì (45) tó kó ẹrù…
ONSA Àtí CBN Ṣé Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Látí Jẹ́ Kí Ètò Ọrọ̀-Àjé Múlẹ̀
Ilé-iṣẹ́ tí Oludamọran Ààbò fún Orílẹ̀-èdè (Office of the National Security Adviser ONSA) àtí Bánkì Àpapọ̀ tí Orílẹ̀-èdè (Central Bank of Nigeria CBN) tí darapọ̀ látí kojú àwọn ìpèníjà tí ètò-ọ̀rọ̀ àjé Orílẹ̀-èdè náà.
Ọrọ̀ náà tí…