Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ

This is a category for business news

Ìlàkààkà Ààrẹ Tinubu Láti Mú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Dé Ilẹ̀ Ìlérí Ń So Èso Rere-…

Mínísítà Fún Ohun Àlùmọ́ọ́nì, Ọ̀gbẹ́ni Dele Alake àti Gomina Ìpínlẹ̀ Kaduna Uba Sani ti sàpèjúwe ìgbésẹ̀ ìsèjọba Ààrẹ Bọla Tinubu gẹ́gẹ́ bí èyí tí yóò mú ìyípadà ọ̀tun bá Orílẹ̀-èdè, tí yóò sì sọ ayé…

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ní Ohun Àmúyẹ Fún Ìdàgbàsókè Ọrọ̀ Ajé: Igbákejì Ààrẹ…

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti késí àwọn olùdókòwò ilẹ̀ òkèèrè láti darapọ̀ mọ́ ètò ọrọ̀ ajé Orílẹ̀-èdè náà èyí tí ó ti ń rú gọ́gọ́ sí i, èyí tí yóò mú ìgbòòrò bá ìdókòwò wọn àti ọrọ̀ ajé…

Iréwọlédé, Ẹ Máa Jó Jàgíní-yòdò: Ìjọba Àpapọ̀ Sàgbékalẹ̀ Ilé Iṣẹ́ Fún Ẹ̀yáwó Láti…

Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti sàdéhùn láti mú ìdàgbàsókè bá ìgbáyégbádùn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pẹ̀lú ìsàgbékalẹ̀ ilé iṣẹ́ ètò ẹ̀yáwó Ìgbésẹ̀ náà wáyé láti mú ìgbòòrò bá ẹka ètò…

Ọ̀wọ́ngógó Owó Ọjà Yóò Di Àfìsẹ́yìn Tí Egúngún Ń Fi Aṣọ Ní Ọdún 2025- Ààrẹ Sọ̀rọ̀…

 Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu fi àrídájú hàn pé Òun yóò mú àdíkù bá fífi ọ̀pọ̀lọpọ̀ owó ra ọjà kékeré ti o n waye ni Orilẹ-ede Naijiria láti ìdá mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n nínú ọgọ́rùn-ún (34%) sí ìdá mẹ́ẹ̀dóógún nínú…

Soludo Pè Fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Láti Sàgbékalẹ̀ Ètò Ọrọ̀ Ajé Èyí Tí Yóò Fìdí Múlẹ̀…

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Anambra, Ọ̀jọ̀gbọ́n Charles Soludo ti ké sí tolórí-tẹlẹ́mù láti fọwọ́sowọ́pọ̀ fún ìsàgbékalẹ̀ ètò ọrọ̀ ajé tí ó múná dóko Ó pe ìpè náà níbi àpérò kan tí ó wáyé ní ìlú Abuja…
button