Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ
This is a category for business news
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọyọ ṣe Ètò Ìrọ̀rùn Fún Ìdàgbàsókè Ọrọ̀ Ajé
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọyọ ti se àfirinlẹ̀ ìpinnu ìjọba rẹ láti jẹ́ kí ìpínlẹ̀ náà gba ètò ọrọ̀ ajé láàyè.
Ó fi ọ̀rọ̀ náà léde ní ọ́ọ́fìsì rẹ nígbà tí ó gba àlejò igbákejì alakoso àgbà ti orílẹ̀…
Àrọwà Ti Wá Láti Sọ́ra Fún Àwọn Oníjìbìtì Lórí ọ̀rọ̀ Ìdókoòwò
Àjọ tí ìjọba àpapọ̀ gbèrò láti dá sílẹ̀ fún ìdókoòwò ti ké gbàjarè, ó sì se ìkìlọ̀ láti máse ṣe àmúlò ìkànnì kan lórí ayélujára, National start Up Investment Fund-NISF. Ọ̀nà náà jẹ́ ìgbésẹ̀ jìbìtì…
Ìpínlẹ̀ Edo Ṣé Ìfilọ́lẹ̀ Ọ̀gbin Ìgbà Ẹẹ̀rún 2022 Wọn Pín Ohun-Èlò Ìbomirin
Ìjọba Ipinlẹ Edo tí ṣé ifilọlẹ ogbin Ẹẹ̀rún 2022, wọ́n sì tún pín Ohùn-Èlò Ibòmírín fún àwọn Agbẹ tí wọ́n le ni Ẹẹdẹgbẹ̀tá láti jẹ kí oúnjẹ pọ yanturu kárí ọdún.
FADAMA EDO ni ó ṣé agbatẹru ifilọlẹ yìí labẹ́…
Minisita Ní Nàìjíríà Yóò Ríi Owó tótó Bílíọ̀nù Méjìdínlógún Náírà Nínú Ìfìmọ̀ṣọ̀kan Akáà
Minisita Ọgbin ati Ìdàgbàsókè Ìgbèríko, Dọkítà Mohammad Abubakar jẹ́ kó di mímọ pé Nàìjíríà yóò jèrè ti ótó Bílíọ̀nù Méjìdínlógún Náírà lórí Akáà mọkàndínlógún àládání pẹ̀lú Ìfìmọ̀ṣọ̀kan wá.
Minisita Ní ìjọba…
Ilé Isẹ́ Niger dock Rí Ìtúsílẹ̀ Lẹ́yìn Ìdánilọ́wọ́kọ́ ọlọ́jọ́ Pípẹ́
Ìjọba àpapọ̀ ti fi ìtúsílẹ̀ ilé isẹ́ Niger dock termina ní èbúté òkun ní ìpínlẹ̀ Èkó léde.
Eléyìí wáyé lẹ́yìn tí ilé isẹ́ náà ti gbà láti tẹ̀lé àlàkalẹ̀ òfin àmúsisẹ́ ìjọba. Mínísítà…
Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú Ṣòfin Pé Àwọn Olórí Ààbò Lórí Bí Wọ́n Kò Ṣé Ń Dunadura Pẹlú Ilé Iṣẹ̀ DICON
Ìgbìmọ̀ Aṣojú Ṣòfin lórí Ààbò tí pé gbogbo àwọn olórí ilé-iṣẹ́ ààbò nì orílẹ̀-èdè yìí nítorí bí wọn ṣé kọ̀ láti máa ra òhun ìjà àti ọdọ Defence Industry Corporation of Nigeria (DICON).
Alága ìgbìmọ̀ náà Hon Babajimi Benson, kéde ìpè…
Ilé-ìfowópamọ́, AATIF kéde iye owó mílíọ́ọ́nù mẹ́èdọ́gbọ̀n dọ́là láti pèsè ìdókòwò…
Ní ìlà pẹ̀lú àwọn akitiyan ìjọba láti mú kí gbígbé oúnjẹ wọ̀lú láti ìlu òkèèrè dínkù àti pípèsè oúnjẹ lọ́pọ̀ yanturu,ilé-ìfowópamọ́ Union ti Nàìjíríà àti àjọ adúláwọ̀ tó ń mójútó owó oun ọ̀gbìn…
Owó Tuntun yóò Mú Àgbéga Bá Ọrọ̀ Ajé Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà
Àjọ kan tí kìí se ti ìjọba tí ó ń rí sí ìdàgbàsókè àwùjọ àti ọrọ̀ ajé ti gbé òsùbà káre fún adarí ilé ìfowópamọ́ àpapọ̀ Nàìjíríà, Godwin Emefiele fún ìfiléde láti pààrọ̀ owó náírà
…
Ẹ̀ka Òfurufú Tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Wà Ni Ipò Kejì Tó Dára Jùlọ́ Làgbáyé Lẹyìn Àjàkálẹ̀ Àrùn…
Nàìjíríà wà ní ipò Kejì lẹyìn Columbia nínù Ìgbìmọ̀ apapọ ọkọ òfurufú àgbáyé lori atunto lẹyìn Covid-19.
Mínísítà fún Ọkọ Òfurufú, Alàgbà Hadi Sirika fí ìdí rẹ̀ múlẹ̀ nígbàtí o ń bá àwọn aṣòfin àpapọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sọrọ ní Ọjọ́rú,…
Ilé- Ìfowópamọ́ Àpapọ̀ Ṣe Àfirinlẹ̀ Títa Ilé- Ìfowópamọ́ Polaris
Ilé ìfowópamọ́ ilẹ̀ wa ti fi léde pé títa ilé ìfowópamọ́ Polaris gba ọ̀nà ẹ̀tọ́ àti àlàkalẹ̀ òfin ọrọ̀ ajé ilẹ̀ Nàìjíríà.
Eléyìí jẹ́ àtẹ̀jáde ẹlẹ́ẹ̀kejì gẹ́gẹ́ bí ilé ìgbìmọ̀ asòfin se lu ètò…