Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ
This is a category for business news
Ẹgbẹ́ Àwùjọ Aráàlú Kàn Bẹ̀rẹ̀ Abojuto Àwọn Bánkì Pẹ̀lú Ìlànà CBN Lórí Owó Tuntun
Ẹgbẹ́ àwùjọ aráàlú kàn, National Coalition On Improved Service Delivery (NACOISED) sọ pé òun tí ṣètò látí bẹ̀rẹ̀ abojuto àwọn bánkì ní ìbámu pẹ̀lú àṣẹ àtí ìlànà CBN látí ríi dájú pé àwọn ẹrọ ATM wọ́n ń pọ́ owó 200, 500 àtí 1000 tuntun…
Orílè-èdè Senegal Gbà Àlejò Ààrẹ Nigeria Fún Àpéjọ Tó Dá Lórí Ìṣẹ́-Ọ̀gbìn
Ààrẹ Muhammadu Buhari tí dé sí Dakar, Olú-ìlú Senegal, lori àpéjọ ẹlẹẹkeji irú rẹ̀, tí "Dakar International Conference on Agriculture."
Ààrẹ Buhari ló fí ìlú Èkó sílẹ̀ lọ́ sí orílẹ̀-èdè Senegal lọ́jọ́ Ìṣẹgun lẹ́yìn àbẹ̀wò oníṣẹ́…
Ètò Ti Parí Láti Gbẹ́ Kàǹga Àgbọ́n-ọ̀n-gbẹ Epo Rọ̀bì Ní Ìpínlẹ̀ Nasarawa
Àjọ tí ó ń mójú tó ìpèsè epo rọ̀bì ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ti setán láti gbẹ́ kàǹga epo rọ̀bì alákọ̀kọ́ọ́ iru ́rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Nasarawa, ààrin gbìngbìn Àréwá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà nínú osù kẹta…
ExxonMobil Gbá Ìwé Àdéhùn Wíwá Èpò Ni Ìlú Egypt
Ìjọba Egypt tí fí ayé ẹtọ gbà ExxonMobil láti máà wà èpò àtí gàásì ní Nile Delta, gẹ́gẹ́ bí ilé iṣẹ́ náà ṣé sọ.
Ìròyìn sọ pé ilé iṣẹ́ náà tí ẹ̀kà Ìlú Egypt yóò ṣiṣẹ́ àwọn bulọọki méjì àti ànfààní ìdá ọgọrùn 100%, pẹ̀lú àwọn iṣawari tí…
Ìpínlẹ̀ Edo Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Àgbẹ̀ Ọlọ́sìn Adìẹ
Ìjọba ìpínlẹ̀ Edo, pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn ilé iṣẹ́ ọlọ́sìn Adìẹ yóò se ìrànlọ́wọ́ fún àwọn àgbẹ̀ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (500,000).
Ó fi ọ̀rọ̀ náà léde níbi àpéjọ kan ní Ikpoba, ìjọba…
Owó Egypt Já Wà Lẹ̀ Sí Dọ́là America
Owó Pọun Egypt já wá lẹ̀ sí dọla Améríkà ní 25.90 ní Ọjọ́bọ̀, èyí tó pọ̀jù láàárín ọjọ́ kàn látí ìgbà tí ilé ifowopamọ àpapọ̀ ìlú Egypt jù ọwọ́ sílẹ̀ níyè 14.5% ní ọjọ́ kẹtadinlọgbọn, Oṣù Kẹwàá, ọdún tó kọjá.
International Monetary Fund…
Ilé Iṣẹ́ Ìsàkóso Gbèsè Fi Ìdókoòwò Léde
Ilé isẹ́ tí ó ń se àkóso gbèsè ní orílẹ̀ èdè, The Debt Management Office, se ìfiléde ìdókoòwò alákọ̀kọ́ọ́ ti ọdún 2023.
Ilé isẹ́ náà sọ pé ìdókoòwò náà bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kẹta osù kíní (January 3), tí…
Owó Epo Rọ̀bì Subú Lulẹ̀ Yakata Látàrí Àìrajaja Ọrọ̀ Ajé Lágbàyéé
Owó orí epo ròbì já, látàrí àìsí oníbàárà ní ọjà àgbáyé. eléyìí wáyé ní ọjọ́ kẹrin osù kíní (4th January, 2023).
Ìsubú náà tún wáyé látàrí àfojúsùn àìrajaja ọrọ̀ ajé ní orílẹ̀…
Àtúntẹ̀ Owó Tuntun Jáde Sí Ìlú
Àwọn owó náírà tuntun tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n ṣẹṣẹ ṣé tí ń lọ káàkiri báyìí bí àwọn ile-ifowopamọ ṣé bẹ̀rẹ sí sàn owó náírà tuntun náà fún àwọn oníbárà wọ́n.
Èyí ń wáyé lẹyìn ọsẹ kẹta tí Ààrẹ Muhammadu Buhari ṣé àfihàn àwọn…
NAFDAC Gbé Ẹsẹ̀ Lé Tòmáàtì Tí Ó Tó Mílíọ̀nù Méjì Náírà
Àjọ tí ó ń mójú tó oúnje àti òògùn lílò, National Agency For Food and Drug Administration and Control, NAFDAC ti gbé ẹsẹ̀ lé tòmáàtì eléyìí tí wọn ń tà lọ́nà tí kò bá òfin mu, tí ọ̀pọ̀ nínú rẹ̀ sì ti…