Take a fresh look at your lifestyle.

ExxonMobil Gbá Ìwé Àdéhùn Wíwá Èpò Ni Ìlú Egypt

0 161

Ìjọba Egypt tí fí ayé ẹtọ gbà ExxonMobil láti máà wà èpò àtí gàásì ní Nile Delta, gẹ́gẹ́ bí ilé iṣẹ́ náà ṣé sọ.

Ìròyìn sọ pé ilé iṣẹ́ náà tí ẹ̀kà Ìlú Egypt yóò ṣiṣẹ́ àwọn bulọọki méjì àti ànfààní ìdá ọgọrùn 100%, pẹ̀lú àwọn iṣawari tí a n’ireti látí bẹ̀rẹ ní ọdún yìí.

Nibayii, ìwé àṣẹ̀ awọn bulọọki wọ̀nyí, èyí tí yóò ṣé ìgbà láàyè fún bí kilomita 11,000, àtúnṣe ṣí tún lè bá ìwé àdéhùn náà síwájú sí.

Lekan Orenuga

Leave A Reply

Your email address will not be published.