Take a fresh look at your lifestyle.

Ètò Ti Parí Láti Gbẹ́ Kàǹga Àgbọ́n-ọ̀n-gbẹ Epo Rọ̀bì Ní Ìpínlẹ̀ Nasarawa

0 167

Àjọ tí ó ń mójú tó ìpèsè epo rọ̀bì ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ti setán láti gbẹ́ kàǹga epo rọ̀bì  alákọ̀kọ́ọ́ iru ́rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Nasarawa, ààrin gbìngbìn Àréwá orílẹ̀ èdè  Nàìjíríà nínú osù kẹta ọdún 2023.

 

Adarí ilé iṣẹ́ náà Mallam Mele Kyari sísọ lójú ọ̀rọ̀ náà nígbà tí Gómìnà ìpínlẹ̀ Nasarawa, Onímọ̀ Ẹ̀rọ Abdullahi Sule kó àwọn èèkàn ìpínlẹ̀ náà sòdí láti sàbẹ̀wò sí ilé iṣẹ́ epo rọ̀bì ní ìlú Abuja.

 

Gómìnà lu àrẹ Buhari lọ́gọ ẹnu fún àtìlẹyìn rẹ̀, Ó sì fi àrídájú hàn pé ìpínlẹ̀ náà yóò fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ìjọba àpapọ̀ àti ilé iṣẹ́ epo rọ̀bì fún ìkẹ́ṣẹjárí ètò náà.

Leave A Reply

Your email address will not be published.