Ẹgbẹ́ àwùjọ aráàlú kàn, National Coalition On Improved Service Delivery (NACOISED) sọ pé òun tí ṣètò látí bẹ̀rẹ̀ abojuto àwọn bánkì ní ìbámu pẹ̀lú àṣẹ àtí ìlànà CBN látí ríi dájú pé àwọn ẹrọ ATM wọ́n ń pọ́ owó 200, 500 àtí 1000 tuntun nìkàn.
Adari àjọ náà, Azor, ṣé ìkéde náà làkókò tó ń bá àwọn òníròyìn sọrọ ní Awka, Olú-ìlú, ìpínlẹ̀ Anambra.
O sọ pé ẹgbẹ́ náà ṣé àkíyèsí pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn bánkì ó tẹ̀ lé ìlànà ní ìbámu pẹ̀lú ìtọ́sọ́nà CBN àtí pé èyí tí fà ijaya láàrín àwọn àrà ìlú, pẹ̀lú bí CBN tí ṣé pinu látí má fí ọjọ́ kún ọjọ́ náà.
Ẹgbẹ́ náà ṣé ìlérí láti tẹ̀ síwájú lórí abojuto náà títí tí àwọn àrà ìlú tí ọrọ̀ náà kàn yóò fí pàárọ̀ owó àtijọ́ sí tuntun.
Lekan Orenuga
[…] Tún kà nípa: Ẹgbẹ́ Àwùjọ Aráàlú Kàn Bẹ̀rẹ̀ Abojuto Àwọn Bánkì Pẹ̀lú Ìlànà CBN Lór… […]