2023: Àwọn Ọmọ Ẹgbẹ NNPP Mẹ́rin Kéde Ìdarapọ̀ Wọn Mọ́ Olùdíje Ààrẹ Ẹgbẹ́ APC
Ní ọjọ ọjọ́rú, àwọn ọmọ ẹgbẹ́ New Nigeria Peoples Party (NNPP) mẹ́rin ní Ìpínlè Ọ̀sun kéde ìsàtìlẹ́yìn Òǹdíje Ààrẹ nínú ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Ọ̀gbẹ́ni Senator Bọ́láTinúbú.
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ mẹ́rin ọ̀hún nìyì:
Clement Bamigbola, láti Osun…