Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta Oníṣègùn Òyìnbó Kúrò Nì Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà- Àjọ Ètò Ìlera

0 113

 

Àwọn onímọ̀ etò ìlera àti ti ìtójú eyín ti Orílẹ̀ èdè Naijiria ti sọ pe Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta Onísègùn Òyìnbó nínú ẹ̀ka kọ̀ọ̀kan isẹ́ ètò ìlera ló ti fi isẹ́ sílẹ̀ lọ sí ìlú ọba láti lọ máa sisẹ́.̀

Olórí ẹgbẹ́, Dọ́kítà Victor Makanjuọla sọ èyí nígbà tó ń dáhùn àwọn ìbéèrè láti ọ̀dọ̀ àwọn oníròyìn ní kété lẹ́yìn ìpàdè àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ní ìlú Benin.

Gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ, àwọn àgbà àgbà nínú ètò iṣẹ́ ìsègùn ti òyìnbó tí wọ́n tó ẹni àádọ̀ta ọdún lọ́jọ́ orí pẹ̀lú ìrírí, tí wọ́n ti fẹ́ fẹ̀yìn tì lẹ́nu isẹ́ ni orílẹ̀-ẹ̀dẹ yìí níláti dá dúró láti kọ́ àwọn ọ̀jọ̀wẹ́wẹ́ àti àwọn akéẹ̀kọ́ onísègùn òyìnbó lápapọ̀ kí àyipadà rere tó le wà ní orílẹ̀ èdè yìí.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave A Reply

Your email address will not be published.