Take a fresh look at your lifestyle.

Òtúbánjọ Gbá Bọ́ọ̀lù UEFA Conference League Goal Ti Ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ Sí Àwọ̀n

0 93Agbaábọ̀ọ̀lu Nàìjíríà, Yusuf Otubanjo ti gba ẹ̀yẹ UEFA Conference League Goal ti Ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀.

Ó gbá bóòlù náà sí àwọ̀n ní ìṣẹ́jú  mẹ́tàdínlógoójì tí eré bẹ̀rẹ̀ fún ikọ̀ rẹ̀ ti Armenian side FC ti wọn sì lọ alátakò wọn to n jẹ Slovan Bratislava túútúú pẹ̀lú àmìn ayò méjì ṣí ọdo.

Góòlù rẹ̀ wá léyìn tí ẹlẹgbẹ́ rẹ̀, Artak Darshayan ti kọ́kọ́ gbá bọ́ọ̀lù wọlé.
Bíborí náà jẹ́ kí ikọ̀ Pyunik lọ sí ipele Kejì ní Ìsòrí H leyin FC Basel.

Òtúbánjo ni ìrètí wà pé yóò sì tún gbá ọ̀pọ̀lọpọ̀ bọ́ọ̀lù wọlé láti gbé ikọ̀ rẹ̀ wọ ipele tókàn nínú líìgì ti Conference

Bótilẹ̀jẹ́pé o n ṣe àtìpó ní Orílẹ̀-èdè Armenia, yóò sì tún tẹ̀síwájú lọ se bẹbẹ ní orílè-èdè Austria.

Ọmọ ọgbọ̀n ọdún náà tí gba bóòlù abélé nígbà kan rí pẹ̀lu Crown FC of Ògbómòṣhó ní orílè-èdè Nàìjíríà.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave A Reply

Your email address will not be published.