Browsing Category
Uncategorized
Ààrẹ Tinubu Gbàdúrà Fún Àwọn Ènìyàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ni Saudi Arabia.
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bola Ahmed Tinubu ti gbàdúrà fún àlàáfíà àti ìdàgbàsókè Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti fún gbogbo àwọn ènìyàn nbè.
Ààrẹ to wà ni ìlú Mecca báyìí ni Orílẹ̀-èdè Saudi Arabia láti lo gbàdúrà fún àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè…
Ààrẹ Tinubu buwọ́lu ìdásílẹ̀ àwọn ilé-èkọ́ gíga tuntun méje
Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bọla Ahmed Tinubu ti buwọ́lu ìdàsílẹ̀ àwọn ilé-èkọ́ gíga tuntun méje lórílẹ̀-èdè ní kíákíá láti túnbọ̀ jẹ́ kí ètò ẹ̀kọ́ tó yè koro wà lárọwọ́tó fún àwọn ènìyàn.
Iyipada…
Makinde Kẹ́dùn Ikú Ọba Àwọn Ẹ̀yà Ìgbò Ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti kẹ́dùn ikú Eze Ndigbo Ilẹ Ìbàdàn, Omowe Alex Anozie tíì ṣe Oba àwọn ẹ̀yà Ìgbò to wa ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, to sì ṣe àpèjúwe ikú rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi ohun tó dunni jọjọ.
Gómìnà, ẹni tó ránṣẹ́ ìbánikẹ́dùn yìí…
Ẹgbẹ́ Àwọn Oníròyìn VON Ké Gbàjarè Síta Bí Wọ́n Ṣe Pàdánù Ọ̀kan Lára Àwọn Akọ̀ròyìn Wọn, Hamisu…
Pẹ̀lú Ibanujẹ Ọkàn ni Ẹgbẹ́ Àwọn Oníròyìn VON gba iroyin Ibanujẹ ikú Hamisu Danjigba, Akoroyin fún Ilé Akede Nàíjíríà (VON) ní Ìpínlẹ̀ Zamfara, iṣẹlẹ ibanujẹ yii to ṣele láti ọwọ́ àwọn ajínigbé.
Ikú rẹẹ̀ jẹ nkan Ibanujẹ tó tún ran wa létí…
Gómìnà Ọyọ buwọ́lu yíyan ọba Ṣoun ti ìlú Ogbomọsọ tuntun
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọyọ, Seyi Makinde, ti buwọ́lu yíyan ọmọ ọba Afọlabi Ghandi Ọlaoye gẹ́gẹ́ bí Ṣoun ti ìlú Ogbomọsọ tuntun.
Kọmiṣọna fun ijọba ibilẹ ati ọrọ Oye, Olusegun Olayiwola, sọ eyi ninu ọrọ rẹ kan pe, kikede yii wa lẹyin eto…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara Bẹ̀rẹ̀ Pínpín Ìrẹsì
Ní ọ̀nà láti jẹ́ kí ìrora yíyọ owó orí epo tó múwá fún àwọn ènìyàn, ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara ti bẹ̀rẹ̀ sí ní pín ìrẹsì fún àwọn tó kù díẹ káàtọ fún ni àwùjọ rẹ̀.
Bí àwọn tó wà ní ìdí ètò náà se sọ, wọ́n ń gbìyànjú láti pín àpò…
Ìpínlẹ̀ Benue: Ó lé Ẹgbẹ̀rún Mẹ́wàá Àwọn Ọmọdé Tó Jẹ Ànfààní Ètò Nípa Aràn.
Àwọn ọmọ kékèké to lè ní ẹgbẹrun mẹwàá ni o jẹ ànfààní ogún tó n dènà Aràn Lára ni ìpínlẹ̀ Benue.
Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Benue ni gbáko ni ṣe agbáterù ètò náà
Àwọn ìbílẹ̀ mẹ́ta ni ìpínlẹ̀ Benue ni àwọn ẹtọ náà ti wáyé, Ipav,…
Nàìjíríà ní kò sí ǹǹkan tó jọ pé a ń ṣe àtúnyàn àwọn alákòóso ilé-iṣẹ́ ìjọba
Ijọba Nàìjíríà ti sọ pé kò sí n ńkan tó jọ pé a ń ṣe àtúnyàn àwọn alákòóso ilé-iṣẹ́ ìjọba.
Eleyii jẹ idahun si ijabọ kan ti iwe iroyin Punch ọjọ Aiku gbe jade, ni oju ewe kẹfa, ti akọle rẹ jẹ: ‘FG ṣetan lati gbe…
Ààrẹ Tinubu ṣe ṣàdàńkátà fún oníṣòwò pàtàkì Abdul Rabiu ní ọdún mẹ́tàlé-lọ́gọ́ta
Ààrẹ Bọla Tinubu ti fi oríyìn ránṣẹ́ sí aṣiwájú oníṣòwò tí ó tún jẹ́ olójú àánú, Alhaji Abdul Rabiu, olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ BUA àti alákóso Abdul Samad Rabiu Adúláwọ̀ (ASR Africa), fún ayeyẹ ọdún kẹtàlé-lọ́gọ́ta…
Ìwádìí Bẹ̀rẹ̀ Lórí Ọkọ̀ Òfúrufú Agbéra Pá Tó Já Lulẹ̀
Àjọ Nigerian Safety Investigation Bureau (NSIB) ti bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lórí ìjàmbá ọkọ̀ òfúrufú mọ́ḿbé Jabiru J430 tó jà lulẹ̀ ní agbègbè Ọba Akran, Ikeja, ìlú Èkó ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun.
Ọkọ̀ òfúrufú agbéra pá mọ́ḿbé ti nọ́ḿbà…