Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌDÁRAYÀ

This is a category for sport news

Látàrí Rúkè-rúdò Tí Ó Wáyé Lásìkò Eré Ìdárayá : Àjọ NPFL Jẹ Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ̀lù…

Àjọ Alákòso  Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ̀lù Abẹ́lé ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti jẹ Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ̀lù El-Kanemi níyà látàrí bí wọ́n se kùnà láti se ètò tí ó múná dóko lásìkò ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ tí ó wáyé láàrin ẹgbẹ́…

Àjọ CAA Yan Afunfèrè Rẹfirí Ọmọ Nàìjíríà Fún Ìdíje Tí Ọjọ́ Orí Àwọn Akópa Kò Kọjá Ogún Ọdún Ní…

Àjọ Confederation of Africa Athletics (CAA) ti yan Omatseye Nesiama tó jẹ́ adarí àjọ Athletics Federation of Nigeria (AFN) nígbà kan ri gẹgẹbí afunfèrè Rẹfirí  ìdíje alápapọ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹta Adúláwọ̀ ti Ọjọ́ orí àwọn akópa kò kọjá Ogún Ọdún ti…
button