Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÁRAYÀ
This is a category for sport news
Ẹ̀yìn Ológbò Kìí Balẹ̀, Màá Lọ Túra Mú -Olowu
Afesekubiojo ọmọ Naijiria, Taiwo Olowu, ti so fún àwọn ololufẹ rẹ pe oun yóò tura mu leyin alubami ti ojugba rẹ, Khuseyn Baysangurov, ọmọ ilẹ Russia fi se ni abala ìkíni ijakadi ni idije IBA Champions to waye ni Sochi, Russia.…
Idije Île Adulawo Ọdún 2023: Offiong Edem Gba Àmì Ẹyẹ Fàdákà Àkọ́kọ́ Fún Nàìjíríà
Idije Île Adulawo Ọdún 2023: Offiong Edwm Gba Àmì Ẹyẹ Fàdákà Àkọ́kọ́ Fún Nàìjíríà
Ọmọ Nàìjíríà, Offiong Edwm ti gba àmì ẹ̀yẹ Fadaka àkọ́kọ́ ni idije ẹlẹ́ẹkẹtàlá ti ilẹ̀ Adulawọ to n waye ni orílẹ̀-èdè Ghana ninu ìdíje ti bọọlu ẹlẹ́yìn…
Àìsàn Jẹjẹrẹ Sekúpa Asọ́lé Fún Ikọ̀ Agbábọ́ọ̀lù Super Falcons Tẹ́lẹ̀rí, Aluko Oseni
Asọ́lé fún ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Super Falcons tẹ́lẹ̀rí, Bidemi Aluko-Oseni ti papòdà lẹ́yìn ìgbà tí ó wàyá ìjà pẹ̀lú àìsàn jẹjẹrẹ fún ọdún mẹ́jọ
Àjọ agbábọ́ọ̀lù ni ó fi ọ̀rọ̀ náà léde ní ọjọ́…
Nwabali Gba Oríyìn Káàbọ̀ Ọmọ Ọ̀dọ̀ Rere Láti Ọ̀dọ̀ Ikọ̀ Chippa United
Ọlọ́wọ́ ẹ̀mú Ikọ̀ Super Eagles Naijiria ti gba káàbọ̀ ọmọ ọ̀dọ̀ rere lati ọdọ ikọ̀ Chippa United ti South Africa to ti n gba bọọlu jẹun latari aseyege alailẹgbẹ rẹ ni ìdíje odun 2023 Africa Cup of Nations (AFCON) to wáyé ni Cote…
Akọ́ni-mọ̀ọ́gbá Chelsea Pochettino Pe Ìpè Fún Sùúrù
Akọ́ni-mọ̀ọ́gbá Mauricio Pochettino ti rọ àwọn Oludasile ikọ̀ Chelsea lati tubọ ni sùúrù kí wọn sì tún fún òun ní ààyè diẹ si lati gbe ikọ̀ náà padà sí ipò Olubori wọn atijọ, kí tábìlì Lígìì sí yi padà sí ibí ire fún wọn.…
Balógun Ìkọ Liverpool Fí Orí Gbá Ife ‘Carabao Cup’ Fún Ìkọ Rẹ̀
Balógun ìkọ Liverpool Virgil van Dijk fí orí gbá bọ́ọ̀lù sàwọ̀n ní ọgọrùn ìṣẹjú lè méjì dín lógún (118th min) látí bóri ìkọ Chelsea níbí ìparí idije Carabao Cup ní Pápá ìṣèré Wembley ní ọjọ́ Àìkú.
Liverpool bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú Cody Gakpo ní…
Ààrẹ Tinubu Kéde Ìbẹ̀rẹ̀ Ìdíje Eré Àwọn Ọlọ́pàá Nàìjíríà Ní Ìbàdàn
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bola Ahmed Tinubu, ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, kéde ìbẹ̀rẹ̀ ìdíje eré àwọn Ọlọ́pàá (Biennial Police Game BIPOGA) ẹlẹẹkẹrinla tí wọ́n pé ní "Oluyole 2024".
Nígbà tó ń kéde iṣide ètò náà ní Lekan Salami Sport Complex,…
NPFL: Ìfẹsẹ́wọ́nsẹ́ Bendel Insurance Àtí Enyimba Gbóná Gidigidi, Nígbàtí Rangers Lú Doma United
Enyimba FC tó gbá ife ẹyẹ́ 'Nigeria Premier Football League NPFL' tí ọdún tó kọjá gbá àmì ayò 0-0 pẹ̀lú Bendel Insurance nínú ìdíje náà, nígbà tí Rangers International lú olúgbàlejò rẹ̀ Doma United ní àmì ayò 1-0 lọ́jọ́ Àbámẹ́ta ní pápá…
Javelin: Ọ̀gbẹ́ni Kure Fìtàn Balẹ̀ Nínú Ìdíje MTNChamps/AFN Ní Ìpínlẹ̀ Delta
Olùborí irin jíjù (Javelin) ní orílẹ̀-èdè yii, Samuel Kure tún ti fakọyọ nínú ìdíje ti MTNChamps/AFN National Trials ọdún 2024 nigbati o ju Personal Best (PB) tuntun to sí gbegba oroke laarin awọn okunrin ni ipinle Delta.
Kure…
Alves Wọ Ẹ̀wọ̀n látàrí Ẹ̀sùn Ìfipá-Báni-Lòpọ̀
Ilé Ẹjọ́ Gíga Catalonia fi agbábọ́ọ̀lù fún Orílẹ̀-èdè Brazil tẹ́lẹ̀rí Dani Alves sí ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́rin àbọ̀ látàrí ẹ̀sùn ìfipá-báni-lòpọ̀ tí ó wáyé ní Barcelona ní ọdún 2022
Ilé ẹjọ́ pàṣẹ kí Alves…