Browsing Category
ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ
This is a category for politics news
2027: Míní́sítà fún Iṣẹ́ buwọ́lu èròńgbà Gómìnà Nwifuru lóríi sáà kejì
Gómìnà tó ṣẹ̀ṣẹ̀ kúrò ní ìpínlẹ̀ Ebonyi tí ó jẹ́ Mínísítà fún ètò ìṣẹ́ lọ́wọ́ báyìí, Sẹ́nétọ̀ David Umahi ti sọ pé òun ti tẹ́wọ́gba àtúnyàn Gómìnà Francis Nwifuru fún sáà kejì lórí oyè nínú ìbò…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Anambra Buwólu Àbádòfin Ètò Ìsúná Ti Ọdún 2025
Gómìnà Ìpínlẹ Anambra, Ọ̀jọ̀gbọ́n Chukwuma Soludo, ní ọjọ́ Ajé ti buwólu àbádòfin ètò ìsúná ti ọdún 2025, èyí tí ó wáyé ní ilé ìgbé gómìnà, ni Amawbia, Ìpínlẹ̀ Anambra
Àbádòfin náà lé díẹ̀ ní…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kebbi Tẹ́ Pẹpẹ Àbà Ètò Ìsúná Ọdún 2025 Síwájú Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin
Gómìnà ìpínlẹ̀ Kebbi, Nasir Idris ti tẹ́ pẹpẹ àbá ìsúná ti ọdún 2025 síwájú ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ naa èyí tí ó tó bílíọ̀nù ẹgbẹ̀ta dín nígba (N580b) fún àgbéyẹ̀wò àti bíbuwọ́lù
Àbá…
Ògúnná Gbòǹgbò Kan Nínú Ẹgbẹ́ Òsèlú PDP Se Ìtorẹ Àánú Fún Àwọn Ògo Wẹẹrẹ Ní…
Èèkàn kan nínú ẹgbẹ́ òsèlú PDP ẹka ti ìpínlẹ̀ Sokoto, Alhaji Faruku Sarkin Fada ti gbáradì láti se ètò dídábẹ́ fún àwọn ògo wẹẹrẹ tí kò dín ní ẹgbẹ̀rún kan ní ìjoba ìbílẹ̀ méjì, ní Ìpínlẹ̀ Sokoto
…
Nàìjíríà Fi Sísetán Wọn Hàn Láti Ṣiṣẹ́ Pọ̀ Pẹ̀lú Ààrẹ Asẹ̀sẹ̀yàn Ilẹ̀ Amẹrika, Trump
Orilẹ̀-ède Nàìjíríà ti fi sísetán wọn hàn lati siṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú Ààrẹ Asẹ̀sẹ̀yàn ẹlẹ́ẹ̀kẹtadínláàdọ̀ta orilẹ̀-ède Amẹrika, Donald Trump.
Mínísítà orilẹ-ède yíì nipa ìròyìn sọ pé, orilẹ-ède Nàìjíríà wa bákan náà pèlú orilẹ-ède…
Ọmọ-Bíbí Nàìjíríà, Kemi Badenoch Dí Olórí Ẹgbẹ́ Òṣèlú ‘Conservative’ Tí Biritiko
Ọmọ bíbí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Kemi Adegoke Badenoch ni wọ́n tí dìbo yàn gẹ́gẹ́ bíi olórí túntún fún ẹgbẹ́ òṣèlú 'Conservative' tí Orílẹ̀-èdè Biritiko.
Kemi, tó dàgbà sí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lẹ́yìn ìbí rẹ̀ ní Orílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì, dí…
Ẹgbẹ́ Òṣèlú BDP Tó Ń Se Ìjọba Lọ́wọ́ Fìdí Rẹmi Nínú Ètò Ìdìbò Ni Orílẹ̀-èdè Botswana
Ẹgbẹ́ Òṣèlú Botswana Democratic Party (BDP) ti fìdí rẹmi ninu idibo ọ̀pọ̀ ile asofin ti ọsẹ yíì bi iroyin aladani iwe ìròyìn Mmegi se sọ ati ti ẹ̀rọ asọ̀rọ̀má- gbèsì ti ipinlẹ to gbe èsì ìbò lati bíi ìlàjì Konsituensi jade.…
Ààre Tinubu Sèdárò Alága Ìdìbò Tẹ́lẹ̀rí Humphrey Nwosu Tó Papò Dà
Ààre Bola Ahmed Tinubu ti kedun gidigidi latari iku, Kofesọ̀ Humphrey Nwosu. O jẹ Alaga Idibo, National Electoral Commission (NEC), teleri, o ku ni ile iwosan orilẹ-ede Amerika.
Ààre Tinubu kedun pẹlú ebi ati ọrẹ ẹni ire to lo,…
Látàrí Ètò Ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ondo: Àjọ Elétò Ìdìbò Pàrowà Sí Àwọn…
Àjọ Elétò ìdìbò ti pàrowà sí àwọn oníròyìn láti fi òpin sí ìtànkálẹ̀ ìròyìn òfegé èyí tí ó se é ṣe kí ó wáyé síwájú, lásìkol àti lẹ́yìn ètò ìdìbò sí ipò gómìnà ìpínlẹ̀ Eko
Ọ̀gbẹ́ni Sam…
Ẹgbẹ́ Òsèlú PDP Kéde Ọjọ́ Kejìdínlọ́gbọ̀n Osù kọkànlá Fún Ìpàdé Ìgbìmọ̀
Ẹgbẹ́ òsèlú alátakò ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, PDP, ti kéde ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n osù kọkànlá fún ìpàdé ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́
Nígbà tí ó ń ka àtẹ̀jáde tí ẹgbẹ́ fi ẹnu kò sí lẹ́yìn ìpàdé àpérò tí ó…