Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀ

This is a Nigeria news category

Ẹgbẹ́ Ọmọ Ológun Orílẹ̀-èdè Ṣe Ìfilọ́lẹ̀ ìpàdé Fún Ìdanilẹ́ẹ̀kọ́ Odún 2026.

Ẹgbẹ́ Ọmọ Ológun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti bẹ̀rẹ̀ ìpàdé fún Ìdanilẹ́ẹ̀kọ́ ti odún 2026 pẹ̀lú ètò ati ìlànà ẹ̀kọ́ ẹyi ti àjọ TRADOC ṣe agbáterù re. Nígbà ti o n sọ̀rọ̀ níbi ayẹyẹ náà ọgá àgbà pátá fún ẹgbẹ́ Ọmọ Ológun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà…

Ètò ìṣúná owó Ọdún 2026 Jẹ́ Àtìlẹ́yìn Nlá Fún Ààrẹ Tinubu: Mínísítà Fún Ọ̀rọ̀ Tó Ńlọ

Mínísítà fún ọ̀rọ̀ tó nlọ Alhaji Mohammed Idris so wí pè ẹ̀tọ̀ ìṣúná owó Ọdún 2026 jẹ ohun tí wọ́n fi ọgbọ́n àti làákàyè gbé kalẹ fún àtìlẹ́yìn ijoba Ààrẹ Tinubu. Nínú ọ̀rọ̀ tó jáde láti ẹnu Mallam Rabiu Ibrahim to jẹ ìgbà Kejì pàtàkì…

Gómìnà Seyi Makinde Kéde Ìṣípò-rọpò Nínú Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ Ìṣèjọba Rẹ̀, O Yan Akọ̀wé Ìjọba Tuntun.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti kede Ọ̀jọ̀gbọ́n Musibau Adetunji Babatunde gẹ́gẹ́ bíi Akọ̀wé tuntun fún ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, lẹ́yìn tó yọ Ọ̀jọ̀gbọ́n Olanike Adeyemo tii ṣe akọ̀wé ìjọba tẹlẹ. Eléyìí ló jẹyọ nínú àtẹ̀jáde láti ọwọ́…

Àwọn Ọmọ-ogun Ṣàfihàn Ẹní Tó Ń Ṣètò Ìpara-ẹni Láàrin Ìlú Ní Àríwá-Ìlà Oòrùn

Àwọn Ọmọ-ogun tó ń ṣiṣẹ́ ní Àríwá-Ìlà Oòrùn Nàìjíríà HADIN KAI (OPHK) tí fí Ọ́gbẹ́ni Shariff Umar hàn gẹ́gẹ́ bí ẹní tó ń ṣètò ìpara-ẹni láàrín ìlú pẹ̀lú ado olóró tó ṣẹ̀ṣẹ̀ wáyé, èyí tí àwọn Ológun náà tí gbìyànjú láti dúró. ‎ ‎Èyí ni…

Ààrẹ Tinubu Pàṣẹ Pé Kí Wọ́n Bẹ̀rẹ̀ Sí Máa Wá Àwọn Tó Ṣékọlù Kasuwan Daji ‎

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí pàṣẹ fún Mínísítà fún ààbò, Olórí Àwọn Ológun, Àwọn Olórí Gbogbo Àwọn Ọmọ Ológun, Olórí Àwọn Ọlọ́pàá, àti Olùdarí Àgbà ti Ẹ̀ka Àwọn Iṣẹ́ Ìpínlẹ̀ (DSS) láti wá àwọn tó ṣe ìkọlù sí Kasuwan Daji kí wọ́n sì mú wọn ní…

Àwọn ọmọ ológun ti gba àwon ará ìlú tí wón jí gbé ní ìpínlẹ̀ Borno sílẹ̀

Àwọn ọmọ-ogun ti Operation HADIN KAI (OPHK) tún ti ṣe àṣeyọrí pàtàkì mììràn lẹ́nu iṣẹ́ wọn, nígbà tí wọ́n farabalẹ̀ kán lu àwọn oníjàgídíjàgan kan ní ìjọba ìbílẹ̀ Konduga, ti Ìpínlẹ̀ Borno, léèyí tí ó yọrí…

Ilé-Iṣẹ́ Ọkọ̀ Ojú Irin Nàìjíríà Bẹ̀rẹ̀ Déédé Owó Ojú-Irin  ‎

 ‎Ilé-Iṣẹ́ Ọkọ̀ Ojú-Irin Nàìjíríà (NRC) ti fi dá àwọn arìnrìn-àjò lójú pé wọ́n ń gbìyànjú láti mú kí iṣẹ́ ọkọ̀ ojú irin dára síi, ìtùnú, àti ààbò lórí gbogbo iṣẹ́ ọkọ̀ ojú irin bí wọn ṣe bẹ̀rẹ̀ déédéé owó ọkọ ojú irin náà ní ọjọ́ Àìkú, ọjọ́…
button